Ayẹyẹ Ọjọ àyájọ́ Awọn ọmọde àti EID tí ọdún ileya yìí : Gomina Ọyọ ṣe àdéhùn idaniloju pé awọn ọmọ ile-iwe ti wọn ji àti awọn olukọ ni igbiyanju ìtúsílẹ̀ wọn ti nlọ lọwọ.

Ayẹyẹ Ọjọ àyájọ́ Awọn ọmọde àti EID tí ọdún ileya yìí : Gomina Ọyọ ṣe àdéhùn idaniloju pé awọn ọmọ…

Ka siwaju

Ẹ na ẹnikẹ́ni tí ó bá tako òfin Sharia, Mufti tí Ìlú Iwo, Sheikh Daood Imran Molaasan ti rọ àwọn Mùsùlùmí láti na ẹnikẹ́ni ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tí ó bá tako ìdásílẹ̀ òfin Sharia.

Mufti ti ìlú Iwo, Sheikh Daood Imran Molaasan, ti ro àwọn Mùsùlùmí lati lu ẹnikẹ́ni ni ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti o…

Ka siwaju

Ìjọba Nàìjíríà Na N12.6trillion Lori Gbèsè Ni oṣu mẹsan, na N3.1trillion Nìkan Lori Ìdàgbàsókè Àwọn ohun Amayederun inú Ìlú.

Ìjọba Nàìjíríà Na N12.6trillion Lori Iṣẹ Gbèsè Ni oṣu mẹsan, na N3.1trillion Nìkan Lori Ìdàgbàsókè Àwọn ohun Amayederun inú Ìlú.…

Ka siwaju

Ènìyàn mẹ́wàá ni wọ́n pa, Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá Kwara Fidi Ikolu tí awon agbésùnmọ̀mí ṣe múlẹ̀ ni àárín-òru si agbègbè Yashikira Kwara, ààfin Emir jona, wọ́n jí awon ènìyàn mẹ́wàá gbé lọ.

Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá Kwara Fidi Ikolu awon agbésùnmọ̀mí ni àárín-òru si adugbo Yashikira Kwara, Won so wipe ààfin Emir ti jona,…

Ka siwaju

Ilé ẹjọ́ UK paṣẹ́ pé kí wọ́n lé àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà elẹ́wọ́n tí wọ́n jẹ̀bi ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀ to pọ̀ lẹ́yìn ogun òfin ọlọ́jọ́ pípẹ́ padà sí Nàìjíríà .

Ilé Ẹjọ́ UK paṣẹ́ pé kí wọ́n dá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n jẹ̀bi ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀ pọ̀ sí i…

Ka siwaju

Wọn pa ènìyàn Mẹta ,jí àwọn Mẹ́ẹ̀dógún gbé lọ Bi awọn agbebọn ṣe kọlu àwọn ènìyàn to lọ ṣe àdúrà ni orí òkè Ìjàyè n’ilu Ekerin ìjọba ìbílẹ̀ Ekiti Kwara.

Gẹ́gẹ́ bi ọlọ́pàá ṣe fìdí ìròyìn náà múlẹ̀ pé , ìkọlù náà wáyé ni ọjọ Àbámẹ́ta ọjọ́ ketalélógún, Oṣu Karun…

Ka siwaju