Àjọ FAA ti ilẹ̀ Amẹ́ríkà ti gbé ìdènà kúrò lórí gbogbo àwọn ọkọ̀ òfurufú ní orílẹ̀-èdè náà, wọ́n sì sọ pé kò sí àmì kankan tó fi hàn pé ó jẹ́ ìkọlù nípasẹ̀ ẹ̀rọ ayélujára (cyberattack).

Àjọ FAA ti ilẹ̀ Amẹ́ríkà ti gbé ìdènà kúrò lórí gbogbo àwọn ọkọ̀ òfurufú ní orílẹ̀-èdè náà, wọ́n sì sọ…

Ka siwaju

Àwọn Ọmọ-ogun Pa agbésùnmọ́mí,mú àwọn méjì mìíràn, Wọ́n sì gba ìbọn AK-47 méjì àti àwọn Ohun Èlò Ìjà ní Ìpínlẹ̀ Katsina àti Sokoto.

Àwọn Ọmọ-ogun Pa agbésùnmọ́mí,mú àwọn méjì mìíràn, Wọ́n sì gba ìbọn AK-47 méjì àti àwọn Ohun Èlò Ìjà ní Ìpínlẹ̀…

Ka siwaju

Ọkùnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan ṣe ikọlù sí ọlọ́pàá Malaysia kan pẹ̀lú àdá méjì, ó sì fa àwọn ọgbẹ́ líle koko fún un.

ÌRÒYÌN PÀTÀKÌ: Ọkùnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan kọlù ọ̀ṣẹ́ ọlọ́pàá Malaysia kan pẹ̀lú àdá méjì, ó sì fa àwọn ọgbẹ́…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá mú baba Meghan, ìyàwó Harry Ọmọ-ọba Uk, ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà lórí ẹ̀sùn ìlò-lódi-sí-ẹ̀tọ́-ọmọdé nípa ìbálòpọ̀.

Àwọn ọlọ́pàá mú baba Meghan, ìyàwó Harry Ọmọ-ọba Uk, ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà lórí ẹ̀sùn ìlò-lódi-sí-ẹ̀tọ́-ọmọdé nípa ìbálòpọ̀. Ìyàwó Prince Harry…

Ka siwaju

Chris Pappas jẹ́ ọkùnrin àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ oníbálòpọ̀-kùnrin-sí-kùnrin (gay) ní gbangba nínú ìtàn Amẹrikà tí wọ́n dìbò yàn sínú Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà (Senate); ó sì dúpẹ́ lọ́wọ́ ọkọ rẹ̀.

Àwọn Ìdìbò ní Amẹ́ríkà: Chris Pappas kọ ìtàn gẹ́gẹ́ bí ọkùnrin àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ oníbálòpọ̀-kùnrin-sí-kùnrin (gay) ní gbangba tí…

Ka siwaju

Àwọn ọmọ Nàìjíríà-Amẹ́ríkà mẹ́rin borí nínú àwọn ìdìbò àárín àkókò ní Amẹ́ríkà, nígbà tí ẹni karùn-ún kan ń ṣáájú ní ìpínlẹ̀ Georgia.

Àwọn ọmọ Nàìjíríà-Amẹ́ríkà mẹ́rin ló jáwé olúborí nínú àwọn ìdìbò àárín àkókò ìṣàkóso (midterm elections) ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ní ọjọ́…

Ka siwaju

Abdul El-Sayed di àgbà Aṣofin mùsùlùmí àkọ́kọ́ nínú ìtàn orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. El-sayed ṣẹ́gun Mike Rogers, olùdíje ẹgbẹ́ Republican tí Donald Trump ṣètìlẹ́yìn fún.

ÌRÒYÌN PÀTÀKÌ: Abdul El-Sayed ṣẹ́gun Mike Rogers, olùdíje ẹgbẹ́ Republican tí Donald Trump ṣètìlẹ́yìn fún, láti di Àgbà Aṣòfin (Senator)…

Ka siwaju

Wọ́n fi ọ̀bẹ gún agbábọ́ọ̀lù ọmọ ilẹ̀ Egypt kan pa níta ilé rẹ̀, lẹ́yìn tí wọ́n ní èdèkòyédè wáyé lórí ọ̀rọ̀ ọmọbìnrin kan tí wọ́n da omi sí lára.

Wọ́n fi ọ̀bẹ gún agbábọ́ọ̀lù ọmọ ilẹ̀ Egypt kan pa níta ilé rẹ̀, lẹ́yìn tí wọ́n ní èdèkòyédè wáyé lórí…

Ka siwaju