àwọn ará Ilé-Ifẹ̀ gba àlejò àwọn ọmọ-ogun 204 láti inú Ẹ̀ka-ogun 137 (Battalion 137) ti Ẹgbẹ́-ogun Nàìjíríà.

ÌRÒYÌN PÀTÀKÌ: ILÉ-IFÈ NÍ Ẹ̀KA ỌMỌ-OGUN (BATTALION) !! *ÌKÀNLẸ̀WỌ̀ NÍPA Ẹ̀KA ỌMỌ-OGUN NÀÌJÍRÍÀ (BATTALION 137) NÍ ILÉ-IFÈ* Ní orúkọ àwọn…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá mú ọkùnrin ẹni ọdún mẹ́rìndínlógójì kan tí wọ́n fura sí pé ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn , pẹ̀lú ìbọn ṣiṣláṣìkí (tí wọ́n fi rọ́bà ṣe), àáké, àti oògùn olóró ‘Ice ní ìpínlẹ̀ Èkó.

Àwọn ọlọ́pàá mú ọkùnrin ẹni ọdún mẹ́rìndínlógójì kan tí wọ́n fura sí pé ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn , pẹ̀lú…

Ka siwaju

Ọmọ-ẹgbẹ́ ẹ̀sọ́ àbó asogbo ìpínlẹ̀ Zamfara sọ pé ọkọ̀ òfuurufú kan fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn ọ̀daràn nígbà ìkọlù àtẹ̀mọ́lẹ̀ kan tí ó gba ẹ̀mí àwọn ọmọ-ẹgbẹ́ CPG méje.

Ọmọ-ẹgbẹ́ ẹ̀sọ́ àbó asogbo ìpínlẹ̀ Zamfara sọ pé ọkọ̀ òfuurufú kan fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn ọ̀daràn nígbà ìkọlù àtẹ̀mọ́lẹ̀ kan tí…

Ka siwaju

Ilé ẹjọ́ Magistrate ní Bolade Oshodi dájọ́ ẹ̀wọ̀n oṣù kan fún Nelly Monday tó ń da ìdọ̀tí sínú àgbàrá omi.

Wọ́n fi obìnrin ọmọ ọdún mẹ́tàléláàádọ́ta 53 sẹ́wọ̀n nítorí sísọ ìdọ̀tí sínú ọ̀nà ìṣàn-omi ní Èkó. Ọjọ́ kọkànlá oṣù Kẹsàn-án,…

Ka siwaju

Darhiru Garba ti o jẹ ọmọ ọdun mẹ́tàdínlààdọ́run 87 fi àdá gé ọwọ́ adájọ́ àgbà Dauda Hammam ní Ile-ẹjọ Agba (Chief Magistrate Court 1) ní Adamawa Yola.

Wọn gbe ọkunrin kan ti o jẹ ọmọ ọdun mẹ́tàdínlààdọ́run 87 lọ si Ile-ẹjọ Agba (Chief Magistrate Court I) ni…

Ka siwaju

Àbùkù fún Orílẹ̀-èdè bí Àwọn Ẹgbẹ́ Ọlọ́pàá Méjì ní Nàìjíríà ṣe Kọlu Ara Wọn ní Àdúgbò kan ní Ìpínlẹ̀ Ọṣun; Àwọn Olùgbé Wà nínú Ìpayà nítorí Ìró Ìbọn.

ÌRÒYÌN PÀTÀKÌ: Àbùkù fún Orílẹ̀-èdè bí Àwọn Ẹgbẹ́ Ọlọ́pàá Méjì ní Nàìjíríà ṣe Kọlu Ara Wọn ní Àdúgbò kan ní…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun mú obìnrin kan lẹ́yìn tí ọmọ-ẹgbẹ́ ààbò àdúgbò kan kú nígbà tí wọ́n ń ṣe ìbálòpọ̀ ní ìlú Ilé-Ifẹ̀.

Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun mú obìnrin kan lẹ́yìn tí ọmọ-ẹgbẹ́ ààbò àdúgbò kan kú nígbà tí wọ́n ń ṣe…

Ka siwaju