Ilé-ẹjọ́ ní Èkó ti dá Tajudden Akanbi, ẹni tí wọ́n fẹ̀sùn ìpànìyàn ní Ajiran kàn, dúró láti tún béèrè fún àǹfààní láti jáde lórí ìdánilóhùn (béélì).

ÌRÒYÌN PÀTÀKÌ: Ile-ẹjọ́ ní Èkó Dènà Tajudeen Akanbi, ẹni tí a fẹ̀sùn kan nípa pípa àwọn ènìyàn ní Ajiran, láti…

Ka siwaju

Ìròyìn fi hàn pé ní ọdún kan, àwọn èèyàn 7,825 ló jẹ́ olùfaragbá tí wọ́n jí gbé (kidnapping) ní Nàìjíríà, àwọn 1,142 sì pàdánù ẹ̀mí wọn, nígbà tí wọ́n san owó ìtúsílẹ̀ tó tó bíi bílíọ̀nù 7.8 náírà.

Ìròyìn fi hàn pé ní ọdún kan, àwọn èèyàn 7,825 ló jẹ́ olùfaragbá tí wọ́n jí gbé (kidnapping) ní Nàìjíríà,…

Ka siwaju