‘Ẹ jọ̀wọ́, ẹ ṣàánú wa’: Àwọn ẹbí,, ìyá bàbá rawọ ẹ̀bẹ̀ fún Gómìnà àti Emir Ilorin ìpínlẹ̀ Kwara láti gba àwọn ọmọ tí àwọn agbésùnmọ́mí jí gbé là.Ẹ jọ̀wọ́, ẹ ṣàánú wa’: Àwọn ẹbí,, ìyá bàbá rawọ ẹ̀bẹ̀ fún Gómìnà àti Emir Ilorin ìpínlẹ̀ Kwara láti gba àwọn ọmọ tí àwọn agbésùnmọ́mí jí gbé là.

‘Ẹ Jọ̀wọ́, Ẹ Ṣe Àánú Fún Wa’: Àwọn Ìdílé Bẹ̀bẹ̀ fún Gómìnà Kwara àti Emir Láti Gba Àwọn Ọmọ tí…

Ka siwaju

Awọn Agbéṣùnmọ̀mí ji awọn ọmọ ile-iwe mẹjọ ti Gateway ICT Polytechnic gbe ni ipinlẹ Ogun, ile-iwe náà si fagilé àwọn ìdánwò tí wọ́n fẹ́ ṣe ni ọjọ́bọ̀ .

Awọn Agbéṣùnmọ̀mí ji awọn ọmọ ile-iwe mẹjọ ti Gateway ICT Polytechnic gbe ni ipinlẹ Ogun, ile-iwe náà si fagilé àwọn…

Ka siwaju

Ó pọn dandan fún APC láti borí nínú ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun,’ Alága Àpapọ̀ sọ bẹ́ẹ̀; ó ní wọn yóò kó àwọn Gómìnà, àwọn Àgbà-òjíṣẹ́, àti àwọn mìíràn wá láti kópa nínú ìdìbò náà.’A gbọ́dọ̀ borí nínú ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun fún ẹgbẹ́ APC,’ ni Alága Orílẹ̀-èdè sọ; yóò sì kó àwọn Gómìnà, àwọn Mínísítà, àti àwọn mìíràn wá láti kópa nínú ìdìbò náà.

Ó pọn dandan fún APC láti borí nínú ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun,’ Alága Àpapọ̀ sọ bẹ́ẹ̀; ó ní wọn yóò kó…

Ka siwaju

Ọlọ́pàá Hisbah tí ìpínlẹ̀ Sokoto tí fi òfin de fífúnni ni ẹ̀bùn nígbà ètò ìfihàn ọkọ̀ àti ìyàwó àti lílo olorin DJ níbi ayẹyẹ ìgbéyàwó, wọ́n fi òfin de kí obìnrin jòkó sí ẹgbẹ awakọ̀ kẹ̀kẹ́ Napel.

Ọlọ́pàá Hisbah tí ìpínlẹ̀ Sokoto tí fi òfin de fífúnni ni ẹ̀bùn nígbà ètò ìfihàn ọkọ̀ àti ìyàwó àti lílo…

Ka siwaju

Ọmọ-ogun Nàìjíríà ti gba àmì ẹ̀yẹ ìdánimọ̀ ti Afirika kọntinenti lẹhin ti wọn fún ni orúkọ Ọmọ-ogun Orilẹ-èdè tí ó dára jù lọ ni ilẹ̀ Afirika ni àwọn iṣẹ́ bí wọ́n ṣe jijàkadì pẹ̀lú àwọn ipanilaya agbésùmọ́mí fún ti ọdun 2025 nípasẹ̀ ètò ààbò ilẹ̀ Afrika.

Ọmọ-ogun Nàìjíríà ti gba àmì ẹ̀yẹ ìdánimọ̀ ti Afirika kọntinenti lẹhin ti wọn fún ni orúkọ Ọmọ-ogun Orilẹ-èdè tí ó…

Ka siwaju

Awọn onijagidijagan Agbésùmọ́mí ti o di ihamọra pa awọn ọmọkunrin meji Alaga ẹgbẹ Miyetti Allah ni agbegbe Gusu-ila-oorun, wọn si pa awọn malu rẹ̀ ogójì 40 ni agbegbe kan ni Enugu.

Awọn onijagidijagan Agbésùmọ́mí ti o di ihamọra pa awọn ọmọkunrin meji Alaga ẹgbẹ Miyetti Allah ni agbegbe Gusu-ila-oorun, wọn si…

Ka siwaju

Ẹgbẹ́ kan ní Ilorin kọ̀ láti gba ẹgbẹ́ ààbò Sunday Igboho tí wọ́n ń pè ní ‘Iru Ekun’, wọ́n sì tọ́ka sí àwọn àníyàn nípa èrò láti dá Orílẹ̀-èdè Yorùbá sílẹ̀.

Ẹgbẹ́ kan ní Ilorin kọ̀ láti gba ẹgbẹ́ ààbò Sunday Igboho tí wọ́n ń pè ní ‘Iru Ekun’, wọ́n sì…

Ka siwaju

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé àwọn ọkọ̀ òfuurufú méjì tí wọ́n rà fún iṣẹ́ àbò àti láti mú kí gbígbà ìròyìn àṣírí nípa ọ̀rọ̀ àbò láàrin ìpínlẹ̀ náà túbọ̀ lágbára ti dé.

Gómìnà Makinde sọ pé wọ́n ra ọkọ̀ òfuurufú náà láti lè máa gba ìwífún láti ojú ọ̀run káàkiri Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́;…

Ka siwaju