Àwọn òṣìṣẹ́ Ilé-iṣẹ́ Ètò Ẹ̀kọ́ ṣe ìdíwọ́ fún Mínísítà fún ètò ẹ̀kọ́ Tunji Alausa láti wọlé sí ọ́fíìsì rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Èkó.

Awọn oṣiṣẹ Ile-iṣẹ Eto Ẹkọ ṣe idiwọ fun Alausa lati wọ ọfiisi rẹ. Awọn oṣiṣẹ Ile-iṣẹ Eto Ẹkọ ti Ijọba…

Ka siwaju

Wọ́n yìnbọn pa ‘Emir Ajagungbade’, ọ̀kan lára ​​àwọn alátìlẹ́yìn Gómìnà Adeleke ti ìpínlẹ̀ Osun, ní ìlú Ifẹ̀.

ÌRÒYÌN PÀTÀKÌ: Wọ́n yìnbọn pa ‘Emir Ajagungbade’, ọ̀kan lára ​​àwọn àmì alátìlẹ́yìn Gómìnà Adeleke ti ìpínlẹ̀ Osun, ní ìlú Ifẹ̀.…

Ka siwaju

Ọmọ-ẹgbẹ́ ẹ̀sọ́ àbó asogbo ìpínlẹ̀ Zamfara sọ pé ọkọ̀ òfuurufú kan fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn ọ̀daràn nígbà ìkọlù àtẹ̀mọ́lẹ̀ kan tí ó gba ẹ̀mí àwọn ọmọ-ẹgbẹ́ CPG méje.

Ọmọ-ẹgbẹ́ ẹ̀sọ́ àbó asogbo ìpínlẹ̀ Zamfara sọ pé ọkọ̀ òfuurufú kan fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn ọ̀daràn nígbà ìkọlù àtẹ̀mọ́lẹ̀ kan tí…

Ka siwaju

Ilé ẹjọ́ Magistrate ní Bolade Oshodi dájọ́ ẹ̀wọ̀n oṣù kan fún Nelly Monday tó ń da ìdọ̀tí sínú àgbàrá omi.

Wọ́n fi obìnrin ọmọ ọdún mẹ́tàléláàádọ́ta 53 sẹ́wọ̀n nítorí sísọ ìdọ̀tí sínú ọ̀nà ìṣàn-omi ní Èkó. Ọjọ́ kọkànlá oṣù Kẹsàn-án,…

Ka siwaju

Darhiru Garba ti o jẹ ọmọ ọdun mẹ́tàdínlààdọ́run 87 fi àdá gé ọwọ́ adájọ́ àgbà Dauda Hammam ní Ile-ẹjọ Agba (Chief Magistrate Court 1) ní Adamawa Yola.

Wọn gbe ọkunrin kan ti o jẹ ọmọ ọdun mẹ́tàdínlààdọ́run 87 lọ si Ile-ẹjọ Agba (Chief Magistrate Court I) ni…

Ka siwaju

Àwọn ènìyàn mẹ́rìnlélógún kú lẹ́yìn tí wọ́n mu ‘àgbo oògùn ìbílẹ̀ ’ ní Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ odigbo ìpínlẹ̀ Ondo.

Àwọn ènìyàn mẹ́rìnlélógún kú lẹ́yìn tí wọ́n mu ‘oògùn ìbílẹ̀ ’ kan ní Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ odigbo ìpínlẹ̀ Ondo. Ní…

Ka siwaju