Àwọn ‘Flamingos’ agbábọ́ọ̀lù obìnrin ti Nàìjíríà ṣẹ́gun Japan, wọ́n sì gba Ife àmì Ẹyẹ Agbaye ti FIFA fún Àwọn Obìnrin ti Ọmọ ọdún 17 sí ìsàlẹ̀ (U-17

ÌRÒYÌN PÀTÀKÌ: Àwọn ‘Flamingos’ ti Nàìjíríà ṣẹ́gun Japan, wọ́n sì gba Ife Ẹyẹ Agbaye ti FIFA fún Àwọn Obìnrin ti…

Ka siwaju

Ìjọba Àpapọ̀ Nàìjíríà ti kéde ètò láti mú àwọn ọmọ-ogun kúrò díẹ̀díẹ̀ nínú àwọn iṣẹ́ ààbò inú orílẹ̀-èdè, kí wọ́n sì dá wọn padà sí àgọ́ wọn.

Ìjọba Àpapọ̀ Nàìjíríà ti kéde ètò láti mú àwọn ọmọ-ogun kúrò díẹ̀díẹ̀ nínú àwọn iṣẹ́ ààbò inú orílẹ̀-èdè, kí wọ́n…

Ka siwaju

Àríyànjiyàn lórí ẹni tí ó jẹ́ baba ọmọ Mohbad: Wọ́n gba àpẹẹrẹ DNA lára ​​òkú olóògbé náà àti ọmọ rẹ̀, Liam, lábẹ́ àbójútó Ilé-ẹjọ́.

Àríyànjiyàn lórí ẹni tí ó jẹ́ baba ọmọ Mohbad: Wọ́n gba àpẹẹrẹ DNA lára ​​òkú olóògbé náà àti ọmọ rẹ̀,…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá mú baba Meghan, ìyàwó Harry Ọmọ-ọba Uk, ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà lórí ẹ̀sùn ìlò-lódi-sí-ẹ̀tọ́-ọmọdé nípa ìbálòpọ̀.

Àwọn ọlọ́pàá mú baba Meghan, ìyàwó Harry Ọmọ-ọba Uk, ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà lórí ẹ̀sùn ìlò-lódi-sí-ẹ̀tọ́-ọmọdé nípa ìbálòpọ̀. Ìyàwó Prince Harry…

Ka siwaju

Òṣèré onitiata Kunle Afod ké gbàjarè,ó ra ọwọ́ ẹ̀bẹ̀ ó ṣàròyé nípa àìsí ọkọ̀ ìpè pàjáwìrì aláìsàn láti gbé àwọn tí ó fara pa nínú ìjamba ni pópónà Ibadan-Sagamu.

ÀKÍYÈSÍ PÀTÀKÌ! Ẹ JỌ̀WỌ́, A NÍ LÒ ÌRÀNLỌ́WỌ́! Kunle Afod ń ké pe Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ogun, àwọn òṣìṣẹ́ FRSC, àti…

Ka siwaju

Wọ́n mú ẹni tí wọ́n fura pé ó jẹ́ Agbéṣùnmọ̀mí ní ilé-ìwòsàn kan ní Kaduna, níbi tó lọ láti gba ìtọ́jú fún ọgbẹ́ tí ó ní láti ara ìbọn.

Wọ́n mú ẹni tí wọ́n fura pé ó jẹ́ Agbéṣùnmọ̀mí ní ilé-ìwòsàn kan ní Kaduna, níbi tó lọ láti gba…

Ka siwaju

EFCC n ṣe iwadii ẹni ti o jẹ òṣìṣẹ́ banki tẹlẹ kan lori ẹsun pe o yi owo ti o to N515 million pada lati inu akanti onibara kan.

EFCC Ṣe Iwadii Lori Olùdarí Banki Tẹ́lẹ̀ Kan Nitori Ẹsun Yíyí N515 Mílíọ̀nù Padà Láti Àkọ́ọ́lù Oníbàárà KanSRỌjọ́ karùn-ún oṣù…

Ka siwaju