Skip to content
  • Sunday, 16 August 2026
  • 8:10 pm
  • Tẹle wa
ÀṢÀKẸ́ NEWS
  • Ile
  • ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ
  • ÌṢÈLÚ
  • Ere Idaraya
  • ÌGBÉSÍ AYÉ
  • ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
  • Ẹ̀KỌ́ ÈDÈ YORÙBÁ
  • Home
  • 2026
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Àwọn fulani darandaran pa olóyè ọ̀tún Balógun oluode Mutairu Oladosu ti okelade Ido Ìbàdàn sínú oko tomato rẹ̀.

Asake Apr 14, 2026 1

Àwọn fulani agbésùnmọ̀mí darandaran pa olóyè Otun Balógun Oluode Okelade ni Ìbàdàn.Ọba Wahab Olabamiji ti Okelade Ibadan lo fi idi…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ

China ṣe àkóbá fún orílẹ̀ èdè Iran bí ó ṣe fi amawomáwò ìmòye sí aṣọ ogun Iran.

Asake Apr 14, 2026 0

Kàyéfì ńlá! Bí àwọn ọ̀gá Ológun Iran (IRGC) , ṣe bẹ̀rẹ̀ sí ní yọ okùn ipò ọ̀gá ológun àti àmí…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ

Trump ti dí ojú ọ̀nà tí orílẹ̀ èdè Iran lè gbà gbé epo rọ̀bì kọjá sí àwọn orílẹ̀ èdè mìíràn , bákan náà ni ó tún dí ibi tí Iran lè gbà gbé ọkọ ojú omi wọlé.

Asake Apr 14, 2026 1

Ní alẹ́ ọjọ́ àìkú tíì ṣe ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 2026, ni iléeṣẹ́ ológun Amẹ́ríkà tún kéde wípé ìgbẹ́sẹ̀…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Seyi Makinde fẹ́ yọ Olubadan Ọba Abdulrasheed Adewolu Ladoja kúrò lórí ìtẹ́

Asake Apr 12, 2026 2

Àtẹ̀jáde kan tí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ekiti tẹ́lẹ̀ rí, Ayodele Fayose fi sí orí ìkànnì ayélujára abẹ́yẹfò x rẹ, lo tí…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Ìjọba àpapọ̀ tí kó orúkọ àwọn ọmọ Nàìjíríà síta ,Tukur Mamu, Simon Njoku Ekpa, IPOB, àti àwọn gúrúpù12 mìíràn, tó ń ṣe ìrànlọ́wọ́ àti àtìlẹyìn fún àwọn agbésùnmọ̀mí.

Asake Apr 12, 2026 2

Ìjọba àpapọ̀ tí kó gbogbo orúkọ àwọn ọmọ Nàìjíríà síta ,lára wọn ni Tukur Mamu, Simon Njoku Ekpa,tí ó jẹ…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Ẹ gba ìwé ìrìnnà lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni tí ó bá ní òun kì í ṣe ọmọ Nàìjíríà mọ́, mínísítà ọ̀rọ̀ abẹ́lé Tunji Ojo pàṣẹ fún iléeṣẹ́ tó ń rí sí ìwọlé – jáde Nàìjíríà

Asake Apr 12, 2026 0

Ìjọba àpapọ̀ tí fi òfin tuntun lélẹ̀, ẹnikẹ́ni tí ó bá ní òun kii se ọmọ Nàìjíríà mọ̀ ọ́, ijọba…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Ènìyàn márùn ni àwọn agbesunmobi tún ti pa lára wọn ni T. Dollar, ní Igbatoro ni ìpínlẹ̀ Ondo, Àwọn ará ìlú gbegi di òpópónà ọ́fíìsí Gómìnà ni Akure.

Asake Apr 11, 2026 0

Àwọn ará ìlú se ìfẹ̀hónúhàn láti ké gbàjarè sì etí ìjọba bí àwọn agbesunmobi ṣe n pa àwọn ènìyàn lójoojúmọ́…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Olórí Ọlọ́dẹ àti àwọn Aṣọ́gbó márùn-ún pàdánù ẹ̀mí wọn ni Kwara bí àwọn agbesunmobi ṣe yabo wọn, tí wọ́n sì dáná sún ọkọ̀ àti ọ̀kadà wọn.

Asake Apr 10, 2026 3

Fọ́nrán àti àwòrán tó jáde síta ṣe àfihàn bí àwọn agbesunmobi ṣe dáná sún ọkọ̀ àti ọ̀kadà àwọn Aṣọ́gbó náà,…

Ka siwaju
ÀWỌN ÌRÒYÌN TÍ Ó NÍPA ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Àwọn agbesunmobi yawọ oko ọ̀sìn Adìẹ, wọn yinbon pa ìyá tó ni ọ̀sìn Adìẹ náà àti ọmọ rẹ̀ obìnrin ni agbègbè Igushin Ala Akure North (apá Àríwá Akure)

Asake Apr 10, 2026 3

Àwọn agbesunmobi yinbon pa ìyá àti ọmọ rẹ̀ obìnrin lójú ẹsẹ bí wọ́n ṣe yawọ inú oko ọ̀sìn Adìẹ ni…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí Bokoharam tún ti pa ọ̀gágun O. Braimah lénu isẹ́ bí wọn ṣe ṣe ìkọlù sí ọgbà ológun Benisheikh Borno

Asake Apr 9, 2026 0

Àwọn agbesunmobi ikọ̀ bokoharam pa Ọ̀gágún O. Braimah Alakoso ẹgbẹ́ ọmọ ogún Naijiria tì o jẹ́ ẹ̀ka 29 ikọ̀ ọgbà…

Ka siwaju

Posts pagination

1 … 30 31 32

Iroyin aipẹ

  • Ìdìbò ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Obìnrin oníwà-ipá jàǹdùnkú olóṣèlú kan tí wọ́n ń pè ní ‘Arugba’ halẹ̀ mọ́ àwọn olùdìbò pé òun yóò gé ìka ọwọ́ wọn tí wọn kò bá dìbò fún ẹgbẹ́ APC.
  • Ikọlu sí Agbẹnusọ Ile-igbimọ Ipinle Osun: Afurasi jẹwọ pe oludije ẹgbẹ APC, Eniade, lo gba oun láti pa a, o si tun jẹwọ pe oun yin ibọn lẹẹmeji.
  • Amnesty International tún rọ àwọn aláṣẹ ní Nàìjíríà láti bọ̀wọ̀ fún àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ-ìlú nígbà ìdìbò Gómìnà ní ìpínlẹ̀ Osun.
  • Ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Àwọn ọlọ́pàá pe Sẹ́nátọ̀ Fadahunsi ti ẹgbẹ́ APC wá fún ìbéèrè lórí ọ̀rọ̀ ìhalẹ̀ láti pa àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Accord.
  • Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Adeleke, fi ẹ̀sùn kan àwọn ọlọ́pàá pé wọ́n ní ètò láti mú àwọn aṣáájú ẹgbẹ́ òṣèlú Accord kí wọ́n sì fi wọ́n sẹ́wọ̀n ní Abuja títí tí ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun yóò fi parí.
Iroyin to Nlo
Ìdìbò ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Obìnrin oníwà-ipá jàǹdùnkú olóṣèlú kan tí wọ́n ń pè ní ‘Arugba’ halẹ̀ mọ́ àwọn olùdìbò pé òun yóò gé ìka ọwọ́ wọn tí wọn kò bá dìbò fún ẹgbẹ́ APC.
Aug 13, 2026
Ikọlu sí Agbẹnusọ Ile-igbimọ Ipinle Osun: Afurasi jẹwọ pe oludije ẹgbẹ APC, Eniade, lo gba oun láti pa a, o si tun jẹwọ pe oun yin ibọn lẹẹmeji.
Aug 13, 2026
Amnesty International tún rọ àwọn aláṣẹ ní Nàìjíríà láti bọ̀wọ̀ fún àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ-ìlú nígbà ìdìbò Gómìnà ní ìpínlẹ̀ Osun.
Aug 12, 2026
Ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Àwọn ọlọ́pàá pe Sẹ́nátọ̀ Fadahunsi ti ẹgbẹ́ APC wá fún ìbéèrè lórí ọ̀rọ̀ ìhalẹ̀ láti pa àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Accord.
Aug 12, 2026
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Adeleke, fi ẹ̀sùn kan àwọn ọlọ́pàá pé wọ́n ní ètò láti mú àwọn aṣáájú ẹgbẹ́ òṣèlú Accord kí wọ́n sì fi wọ́n sẹ́wọ̀n ní Abuja títí tí ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun yóò fi parí.
Aug 12, 2026

Asọye aipẹ

  1. ABDULRASAQ ADENIYI SOLIU on Àwọn ọkùnrin mẹ́jọ tí ọjọ́ orí wọn wà láàárín ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún sì méjìlélọ́gbọ̀n ni wọ́n fi ẹ̀sùn kàn lórí ètò láti kọlu ayẹyẹ UFC ti Trump ní Ilé Ààrẹ ni White House.
  2. Lewishow on Ìpayà bí iná ṣe jó ilé ìtajà ike tó wà ni old garage Osogbo tó jẹ́ olú ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀sun.
  3. Timsothyemeri on Ìpayà bí iná ṣe jó ilé ìtajà ike tó wà ni old garage Osogbo tó jẹ́ olú ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀sun.
  4. OLUFEMI OSHIKPOYA on Wọn pa ènìyàn kan, ọpọlọpọ farapa yannayanna bí Ẹgbẹ́ òṣèlú APC àti Accord Party ṣe ja ni Osogbo.
  5. Alma1848 on Ọwọ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ẹdo tẹ afurasí ajínigbé méjì, wọn gba ara ènìyàn tó ti jẹrà méjì padà.
Awọn ẹka
  • ÀWỌN ÌRÒYÌN TÍ Ó NÍPA
  • Ere Idaraya
  • ÌGBÉSÍ AYÉ
  • ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
  • ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ
  • ÌṢÈLÚ
  • Uncategorized
Iroyin ti oti le Ti padanu
News Mart logo

Ni pa wa

Shagam
info@asakenews.com
+212 710-380820
Iroyin Tuntun
Ìdìbò ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Obìnrin oníwà-ipá jàǹdùnkú olóṣèlú kan tí wọ́n ń pè ní ‘Arugba’ halẹ̀ mọ́ àwọn olùdìbò pé òun yóò gé ìka ọwọ́ wọn tí wọn kò bá dìbò fún ẹgbẹ́ APC.
Aug 13, 2026
Ikọlu sí Agbẹnusọ Ile-igbimọ Ipinle Osun: Afurasi jẹwọ pe oludije ẹgbẹ APC, Eniade, lo gba oun láti pa a, o si tun jẹwọ pe oun yin ibọn lẹẹmeji.
Aug 13, 2026
Amnesty International tún rọ àwọn aláṣẹ ní Nàìjíríà láti bọ̀wọ̀ fún àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ-ìlú nígbà ìdìbò Gómìnà ní ìpínlẹ̀ Osun.
Aug 12, 2026
Ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Àwọn ọlọ́pàá pe Sẹ́nátọ̀ Fadahunsi ti ẹgbẹ́ APC wá fún ìbéèrè lórí ọ̀rọ̀ ìhalẹ̀ láti pa àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Accord.
Aug 12, 2026
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Adeleke, fi ẹ̀sùn kan àwọn ọlọ́pàá pé wọ́n ní ètò láti mú àwọn aṣáájú ẹgbẹ́ òṣèlú Accord kí wọ́n sì fi wọ́n sẹ́wọ̀n ní Abuja títí tí ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun yóò fi parí.
Aug 12, 2026
Awọn ẹka
  • ÀWỌN ÌRÒYÌN TÍ Ó NÍPA
  • Ere Idaraya
  • ÌGBÉSÍ AYÉ
  • ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
  • ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ
  • ÌṢÈLÚ
  • Uncategorized
Forukọsilẹ Fun Iwe Iroyin Wa

Se alabapin si iwe iroyin wa lati gba awọn nkan tuntun wa lesekese!

Copyright © 2026 Asake News | Design by Yaagboyaaju Tech

  • Home
  • About
  • Blog
  • Contact