Ṣé ìfẹ́ òtítọ́ ni Eléyìí ni tàbí ìfẹ́ owó

Alákóso àgbà fún ìjọ OPM ní a gbọ́ wípé ó ṣètò àwọn ẹ̀bùn kàǹkà fún arábìnrin tí ó fẹ́ ọmọ rẹ̀ kan tó gbà tọ .

Ọmọ yìí ní a gbọ́ wípé kò fi gbogbo ara pé tán .
Lára àwọn ẹ̀bùn ti o ṣèlérí fún obìnrin tó fẹ́ ọmọ yí ni, owó Oṣù títí láé láé , Ilé ọ̀fẹ́ , MÍLÍỌ́NÙ mẹ́wàá , ìrìn-àjò afẹ́ lọ sìlú òyìnbó , àti ogún MÍLÍỌ́NÙ (niwon igba ti ọmọ náà bá wa láàyè ), àti àwọn ẹ̀bùn mìíràn .
Ẹ̀yin ènìyàn wa ẹ gbọ́ ṣe ìfẹ́ òtítọ́ ni kí á pe eléyìí ni tàbí ìfẹ́ owó?

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *