Ilé ẹjọ́ pàṣẹ pé kí wọ́n gba àwọn dúkìá Mínísítà Agbára iná mọ̀nàmọ́ná tẹ́lẹ̀ rí, Saleh Mamman’s lẹ́yìn tí wọ́n fún ní ẹ̀wọ̀n ọdún Márùndínláàdọ́rin 75.

Ilé ẹjọ́ pàṣẹ pé kí wọ́n gba àwọn dúkìá Mínísítà Agbára iná mọ̀nàmọ́ná tẹ́lẹ̀ rí, Saleh Mamman’s lẹ́yìn tí wọ́n…

Ka siwaju

Trump pé Ààrẹ Fifa Gianni Infantino pé kí ó ṣe àtúnyẹ̀wò ìdadúnró ìdíje kan tí ó fà àríyànjiyàn tí wọ́n fún agbábọ́ọ̀lù Amẹrikà Folarin Balógun lẹ́yìn tí ó gba káàdì pupa sí Bosnia àti Herzegovina.

Trump pé Ààrẹ Fifa Gianni Infantino pé kí ó ṣe àtúnyẹ̀wò ìdadúnró ìdíje kan tí ó fà àríyànjiyàn tí wọ́n…

Ka siwaju

Wọ́n mú Ìyá ọmọ ọdún mẹ́tàdínlààdọ́rin (67) ọmọ Nàìjíríà-Gẹ̀ẹ́sì ní pápákọ̀ òfurufú ìlú Èkó pẹ̀lú 13kg cocaine tí wọ́n fi pamọ́ sínú Egbogi ewéko.

Wọ́n mú Ìyá ọmọ ọdún mẹ́tàdínlààdọ́rin (67) ọmọ Nàìjíríà-Gẹ̀ẹ́sì ní pápákọ̀ òfurufú ìlú Èkó pẹ̀lú 13kg cocaine tí wọ́n fi…

Ka siwaju

Ọlọ́pàá Nàìjíríà ti jẹ́rìí sí ìtúsílẹ̀ àwọn olùjọ́sìn CAC Eda Oniyo ní Ìpínlẹ̀ Ekiti lẹ́yìn tí wọ́n ti lo oṣù mélòó kan pẹ̀lú nínú ìgbèkùn àwọn agbésùnmọ̀mí.

Ọlọ́pàá Nàìjíríà ti jẹ́rìí sí ìtúsílẹ̀ àwọn olùjọ́sìn CAC Eda Oniyo ní Ìpínlẹ̀ Ekiti lẹ́yìn tí wọ́n ti lo oṣù…

Ka siwaju