Olùsọàgùntàn Pásítọ̀ Amos Isah tí wọ́n fi ẹ̀sùn kan pé ó fipa bá ọmọ ọdun mẹ́rìnlá lò pọ̀ nílé ìjọsìn Labuja, lọ ṣe àbẹ̀wò sí ìdílé ọmọ náà ní alẹ́ láti bẹ̀bẹ̀ fún ìdáríjì.

FÍDÍÒ ṣàfihàn Olusoagutan Amos Isah, ti wọn fẹ̀sùn kan pé o fipa bá ọmọ ọdun mẹ́rìnlá 14 yrs lò pọ̀…

Ka siwaju

Ààrẹ Tinubu rán gbákejì rẹ̀ Kashim Shettima lọ sí Ondo fún ti ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọgọ́rùn-ún ọdún DR. Reuben Fasoranti.

Igbákejì Ààrẹ Nàìjíríà Kashim Shettima dé sí Ondo fún ti ayẹyẹ ọgọ́rùn-ún ọdún ọjọ́ ìbí Reuben Fasoranti. Igbákejì orílẹ̀ èdè…

Ka siwaju

Mínísítà tuntun tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn fún iná mọ̀nàmọ́ná Joseph Tegbe figbe ta, Mi kò ṣèlérí pé iná yóò fún oṣù mẹ́ta fún ọmọ Nàìjíríà o.

Minisita ti wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ yan fun Agbára iná mànàmáná , Joseph Olasunkanmi Tegbe, ti kọ awọn iroyin ti o sọ…

Ka siwaju

Ààrẹ Tinubu ti yan Ìyà àárín Arinola Ogbara Banjoko gẹ́gẹ́ bí Alákóso aṣojú lórí ìgbìmò ìṣòwò pàsí pààrọ̀ ọjà ìpínlẹ̀ Èkó.

Ààrẹ Tinubu ti yan Ìyà àárín Arinola Ogbara Banjoko gẹ́gẹ́ bí Alákóso aṣojú lórí ìgbìmò ìṣòwò pàsí pààrọ̀ ọjà ìpínlẹ̀…

Ka siwaju

Ọ̀gá ọlọ́pàá Tunji Disu ń wá àjọṣepọ̀ ìfọwọ́sowopọ̀ àwọn ọlọ́pàá àti àwọn ará ìlú ní gbogbo agbègbè láti ní ètò ààbò tó péye nínú Nàìjíríà.

Ọ̀gá ọlọ́pàá Tunji Disu, n wá , ajọṣepọ ìfọwọ́sowopo àwọn ọlọ́pàá àti àwọn ará ìlú agbègbè láti ni ètò ààbò…

Ka siwaju