Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano fún arábìnrin Naseer Teemahcool ni ipò òṣèlú gẹ́gẹ́ bí alámójútó ètò àwọn obìnrin lẹ́yìn tí ó ṣe àfihàn àwọ̀tẹ́lẹ̀ obìnrin pátá ni níbi ìpolongo ìdìbò 2027 ni Kano.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano tí fún Fatima Naseer Teemahcool, Alaga ti Gida-Gida TikTokers ti o ṣe afihan awọn aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ obìnrin…

Ka siwaju

Ààrẹ Tinubu buwọ́lu ọ̀pọ̀ ilẹ̀ L’abuja fún Reno Omokri, Femi Fani-Kayode àti àwọn ènìyàn tuntun mìíràn tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn láìpẹ́ tó ń soju Nàìjíríà nílẹ̀ òkèèrè.

Wike sọ èyí lásìkò ti o n gba àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba, ìjọba Olómìnira náà lásìkò àbẹ̀wò ìtẹríba si ilé ìjọba…

Ka siwaju

Ààrẹ Tinubu ti buwọ́lu N2bn owó gbà má bínú àtìlẹyìn ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn 27 tí àwọn agbésùnmọ̀mí pa ni March 29,ọjọ́ ìsinmi ọ̀pẹ (palm Sunday) ní Plateau .

Ààrẹ Bola Tinubu ti buwọ́lu N2bn ni àtìlẹyìn iranlọwọ owó gbà má bínú fún àwọn olóògbé 27 tí àwọn agbésùnmọ̀mí…

Ka siwaju

Àwọn ẹlẹ́ṣọ àbò Aṣọ́gbó ti farapa yannayanna,Won pa ènìyàn méjì, tí wọ́n sì tún jí àwọn aráàlú gbé lọ ní ọsan gangan nígbà tí àwọn agbésùnmọ̀mí kọlù Oko Erese oro- àgọ́, Babanla Kwara.

Awọn ará ìlú ti o ba oníròyìn sọrọ sọ pe ìṣẹ̀lẹ̀ náà wáyé ni ọsan ọjọ ìṣẹ́gun, ọjọ́ kejìdnlogbon oṣù…

Ka siwaju

Àwọn agbébọn yawọ ilé ìjọsìn Christ Apostolic church Eda Oniyo ní ìpínlẹ̀ Èkìtì, wón pa Pásítọ̀ ìjọ, wọ́n jí ọ̀pọ̀lọpọ̀ olùjọsìn gbé lọ.Ní dédé ago mẹ́jọ àbọ̀ àṣálẹ́8:30pm, ọjọ́ ìṣẹ́gun .

Àwọn agbébọn yawọ ilé ìjọsìn Christ Apostolic church Eda Oniyo ní ìpínlẹ̀ Èkìtì, wón pa Pásítọ̀ ìjọ, wọ́n jí ọ̀pọ̀lọpọ̀…

Ka siwaju