Àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà tí operations Hadin Kai (OPHK) tí ṣe àṣeyọrí gba àwọn ọmọ ilé ìwé mẹ́wàá tó ń ṣe ìdánwò Neco àti àwọn olùkọ́ tí wọ́n jí gbé sílẹ̀.

Àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà tí operations Hadin Kai (OPHK) tí ṣe àṣeyọrí gba àwọn ọmọ ilé ìwé mẹ́wàá tó ń…

Ka siwaju

Àwọn ọmọ-ogun Nàìjíríà tí tako igbésẹ̀ ijoba apapo Lati Fi awọn apanirun agbésùmọ́mí afemisofo tó Ronupiwada Sínú iṣẹ Ologun, wọn Ibẹru gbígba àbọ̀dè àti àwọn àṣírí Imọye wọn “.

Àwọn ọmọ-ogun Nàìjíríà tí tako igbésẹ̀ ijoba apapo Lati Fi awọn apanirun agbésùmọ́mí afemisofo tó Ronupiwada Sínú iṣẹ Ologun, wọn…

Ka siwaju

Ọlọ́pàá Ọ̀yọ́ àti alága ìjọba ìbílẹ̀ Oorelope ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti tako ipa tí Sunday Igboho kó nípa ìtúsílẹ̀ àwọn ènìyàn olufaragba tí àwọn agbésùmọ́mí jí gbé.

Ọlọ́pàá Ọ̀yọ́ àti alága ìjọba ìbílẹ̀ Oorelope ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tako Ipa Sunday Igboho nínú ìtúsílẹ̀ Àwọn ènìyàn tí fúlàní agbésùnmọ̀mí…

Ka siwaju

Ilé-ẹjọ́ gíga ti ìjọba àpapọ̀ ni ilu Abuja ti dajọ ikú fún Zakaria Garba, ẹni ọdun 37 latari bí ó…

Ka siwaju

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti kéde ọjọ́ ajé tíì ṣe ọjọ́ kọ̀ọ̀kandinlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà Ọdun 2026 yii ni ìdánwò junior WAEC yóò wáyé ní ìpínlẹ̀ náà.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti kéde ọjọ́ ajé tíì ṣe ọjọ́ kọ̀ọ̀kandinlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà Ọdun 2026 yii ni ìdánwò junior WAEC…

Ka siwaju

Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ogun Mú Ọ̀kan lára àwọn ẹ̀ṣọ̀ alábò ọlọ́pàá tó fi ipá já ìbálé Ọ̀dọ́bìnrin Ẹni Ọdún mẹ́rìndínlógún [16], tí wọ́n sì gba ìbọn lọ́wọ́ rẹ̀.

Ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ogun Mú Ọ̀kan lára àwọn ẹ̀ṣọ̀ alábò tó fi ipá já ìbálé Ọ̀dọ́bìnrin Ẹni Ọdún mẹ́rìndínlógún , tí…

Ka siwaju

Boko Haram gé orí àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà, àwọn kan farapa yánnayànna bí wọ́n ṣe ṣe Ìkọlù sí ọgbà ológun ni kùtùkùtù òwúrọ̀ òní ọjọ́ Ẹtì ni ibùdó àwọn ọmọ ogun tó wà ni ìpínlè Borno.

Loni tíì ọjọ́ Ẹtì ọjọ́ Kàrún oṣù kẹfà ọdún 2026 ni àwọn Boko Haram gé orí àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà,…

Ka siwaju