Ẹnikẹ́ni tí ó bá fọwọ́ yí ètò ìdìbò padà, a ó pa á,’ ni Sẹ́nátọ̀ Omo-Agege kìlọ̀ ṣáájú àwọn ìdìbò ọdún 2027, ó sì sọ pé ‘tí o bá yí ìdìbò padà, o ó kú.’

Ẹnikẹ́ni tí ó bá fọwọ́ yí ètò ìdìbò padà, a ó pa á,’ ni Sẹ́nátọ̀ Omo-Agege kìlọ̀ ní ṣáájú àwọn…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Borno mú àwọn ọkùnrin márùn-ún tó wọ aṣọ tí wọ́n kọ pé ‘Tinubu Must Go’ (Tinubu gbọ́dọ̀ kúrò ní ipò) sí, wọ́n sì ti fi wọ́n sẹ́wọ̀n.

Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Borno mú àwọn ọkùnrin márùn-ún tó wọ aṣọ tí wọ́n kọ pé ‘Tinubu Must Go’ (Tinubu…

Ka siwaju

Mo bẹ̀rẹ̀ sí ní lé àwọn ẹ̀mí èṣù, èmí àìrí jáde nígbà tí mo wà ní ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún; kò sì ṣàjèjì sí mi láti kojú àìnífọkànbalẹ̀ tàbí àwọn ọ̀rọ̀ tó jẹ mọ́ ẹgbẹ́ òkùnkùn — Gómìnà Ìpínlẹ̀ Edo, Okpebholo.

Mo bẹ̀rẹ̀ sí ní lé àwọn ẹ̀mí èṣù, èmí àìrí jáde nígbà tí mo wà ní ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún; kò…

Ka siwaju