Ìjọba Nàìjíríà ti mú 327 àwọn Awakùsà tó ń wa kùṣà lọ́nà tí kò bófin mú, pẹ̀lú àwọn afurasí àjèjì ọmọ ilẹ̀ òkèèrè tó ń lo àwọn agbésùnmọ̀mí láti wa kùṣà nínú Nàìjíríà.

ÀṢÀKẸ́ TV NEWS : Ìjọba Nàìjíríà ti Mu 327 Àwọn Awakùsà tó ń wa kùṣà lọ́nà tí kò bófin mú…

Ka siwaju

Ẹ gé iléeṣẹ́ MTN àti DSTV South Africa, Sínetọ̀ Adams Oshiomhole rọ ìjọba pé kí ó yọ iléeṣẹ́ MTN, DSTV kúrò to jẹ́ ti South Africa àti ìwé àṣẹ wọn látàrí fífi ẹ̀mí ọmọ Nàìjíríà ṣòfò.

Sínetọ̀ Adams Oshiomhole rọ ìjọba pé kí ó yọ iléeṣẹ́ MTN, DSTV kúrò to jẹ́ ti South Africa àti ìwé…

Ka siwaju

Arábìnrin Shifawu Alabi ẹni Àádọ́rin Ọdún tó sọnù ni ọjà ọba Ìbàdàn ni wọ́n rí ní Ọ̀sun iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ ọ̀sun ló kéde rẹ̀.

Arábìnrin ìyá àgbàlagbà kan ẹni Àádọ́rin Ọdún Shifawu Alabi tí ó sọnu tí àwọn ẹbí ń wá ní Ọjà ọba…

Ka siwaju