Seyi Makinde ṣe ifilọ́lẹ̀ àti fifisílẹ̀ ọ́fíìsí Ẹ̀ka ẹ̀ṣọ́ ààbò tuntun láti kojú àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ̀mí ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ .

Ní kùtùkùtù òní tíì ṣe ọjọ́ Abameta ọjọ́ keridinlogun oṣù Kàrún ọdún 2026 ni Seyi Makinde ṣe ifilọlẹ ati fifisilẹ…

Ka siwaju

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí ṣe ìkọlù sí Ilé ìwé mẹta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní Ọ̀yọ́:ilé ìwé Baptist Nursery and Primary school, Community Grammar School Esiele àti L. A Primary school, wọn pa Olukọni, jí ọ̀gá àgbà àti ọ̀pọ̀ àwọn ọmọ ilé ìwé gbé lọ.

Awọn Agbéṣùmọ̀mí ṣe ìkọlù sí ile-iwe mẹta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ , wọ́n pa Olukọni,wọn ji Awọn ọmọ ile-iwe ati…

Ka siwaju

Imam Mọ́ṣáláṣí Lọndọnu Abdul Khan ti rí ẹ̀wọ̀n Ogún ọdún he, fún ẹ̀sùn ìfipábá àwọn ọmọdébìnrin lo pọ̀.

Ilé ẹjọ́ Snaresbrook Crown nilu Lọndọnu tí ju Imam Mọ́ṣáláṣí Lọndọnu Abdul Khan sí ẹ̀wọ̀n Ogún ọdún fún ẹ̀sùn ìfipábá…

Ka siwaju

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí ti jí ọ̀gá àgbà iléèwé àti àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ gbé lọ, ní ilé ìwé gírámà Ahoro – Esinele ní ìjọba ìbílẹ̀ Oriire ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.

Awọn Agbéṣùmọ̀mí ti ji ọ̀gá àgbà ilé ìwé ,àti àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gbé lọ nilu Ahoro-Esinele ní ìjọba ìbílẹ̀ Oriire ìpínlẹ̀…

Ka siwaju

Iléeṣẹ́ ọmọ ogun Nàìjíríà Gba àwon ẹ̀rọ Nẹ́tíwọ́kì Starlink irínwó (400) tí wọ́n ní o ní àsopọ̀ mọ́ Iléeṣẹ́ Internet Satellite Elo Musk lọwọ àwọn agbésùnmọ̀mí pẹ̀lú ẹ̀sùn ibasepo ará ìlú.

Àwọn Ọmọ-ogun Nàìjíríà Gba Awọn Ẹrọ Starlink tó ju irínwó (400) lọ lọwọ Awọn Agbéṣùmọ̀mí ti wọn ni ó ní…

Ka siwaju

Ọ̀gá ọlọ́pàá Tunji Disu ti gbẹ́ṣẹ́ lé awọn oniṣẹ POS tó má ń jòkó sí ẹgbẹ́ àgọ́ ọlọ́pàá ní gbogbo Nàìjíríà lórí àwọn ẹ̀sùn Ìlọ́nilọ́wọ́gbà tí wọ́n fi kan àwọn ọlọ́pàá

IGP Ọ̀gá ti gbẹ́ṣẹ́ lé àwọn oníṣẹ́ POS tó ma ń jòkó sí ẹgbẹ́ àgọ́ ọlọ́pàá ní Nàìjíríà Nàìjíríà, ó…

Ka siwaju

Olùsọàgùntàn Pásítọ̀ Amos Isah tí wọ́n fi ẹ̀sùn kan pé ó fipa bá ọmọ ọdun mẹ́rìnlá lò pọ̀ nílé ìjọsìn Labuja, lọ ṣe àbẹ̀wò sí ìdílé ọmọ náà ní alẹ́ láti bẹ̀bẹ̀ fún ìdáríjì.

FÍDÍÒ ṣàfihàn Olusoagutan Amos Isah, ti wọn fẹ̀sùn kan pé o fipa bá ọmọ ọdun mẹ́rìnlá 14 yrs lò pọ̀…

Ka siwaju

Ààrẹ Tinubu rán gbákejì rẹ̀ Kashim Shettima lọ sí Ondo fún ti ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọgọ́rùn-ún ọdún DR. Reuben Fasoranti.

Igbákejì Ààrẹ Nàìjíríà Kashim Shettima dé sí Ondo fún ti ayẹyẹ ọgọ́rùn-ún ọdún ọjọ́ ìbí Reuben Fasoranti. Igbákejì orílẹ̀ èdè…

Ka siwaju

Mínísítà tuntun tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn fún iná mọ̀nàmọ́ná Joseph Tegbe figbe ta, Mi kò ṣèlérí pé iná yóò fún oṣù mẹ́ta fún ọmọ Nàìjíríà o.

Minisita ti wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ yan fun Agbára iná mànàmáná , Joseph Olasunkanmi Tegbe, ti kọ awọn iroyin ti o sọ…

Ka siwaju