Ilé-ẹjọ́ gíga ti ìjọba àpapọ̀ ni ilu Abuja ti dajọ ikú fún Zakaria Garba, ẹni ọdun 37 latari bí ó…

Ka siwaju

Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá Nàìjíríà tí tu ibùdó àwọn Ẹgbẹ ti n ta ènìyàn, fi ọmọ ènìyàn ṣe owó ẹrú káàkiri Nàìjíríà ká , wọn gba àwọn ọmọ ara ilẹ̀ òkèèrè 30 là Ni Abuja àti ní Nasarawa.

Ọlọ́pàá náà sọ pe iwadii bẹ̀rẹ̀ lẹ́hìn àwọn ijabọ oye ti fi ipadanu ti ọpọlọpọ àwọn ọmọ ìlú òkèèrè láàrin…

Ka siwaju

Ààrẹ Tinubu buwọ́lu ọ̀pọ̀ ilẹ̀ L’abuja fún Reno Omokri, Femi Fani-Kayode àti àwọn ènìyàn tuntun mìíràn tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn láìpẹ́ tó ń soju Nàìjíríà nílẹ̀ òkèèrè.

Wike sọ èyí lásìkò ti o n gba àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba, ìjọba Olómìnira náà lásìkò àbẹ̀wò ìtẹríba si ilé ìjọba…

Ka siwaju