Jíjẹ oúnjẹ tòmátò tó bàjẹ́ àti ata eléyìí tí àwọn ènìyàn ń pè ní “ẹ̀ṣà tòmátò” lè fa àìsàn àrùn jẹjẹrẹ sí àgọ́ ara, ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ṣe ìkìlọ̀ àti àwọn onímọ̀ nípa oúnjẹ.

Àwọn tòmátò tí ó bàjẹ́ lè fa ikuna ara ènìyàn, àwọn onímọ̀ nípa oúnjẹ lo sọ bẹ́ẹ̀. Lẹ́yìn ìkìlọ̀ tí…

Ka siwaju

Gómìnà Seyi Makinde sọ pé ìjọba òun Ṣetán lati gbọ́ ohun tí àwọn agbésùnmọ̀mí fẹ́, kí wọn bá wọn dúnàdúrà láti lè gba àwọn ọmọ ilé ìwé àti àwọn olùkọ́ tí wọ́n jí gbé ní ìjọba ìbílẹ̀ Oriire ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ sílẹ̀.

Gómìnà Seyi Makinde sọ pé ìjọba òun Ṣetán lati gbọ́ ohun tí àwọn agbésùnmọ̀mí fẹ́, kí wọn bá wọn dúnàdúrà…

Ka siwaju

Davido gba ìsinmi lenu isẹ orin kíkọ láti ṣáájú àwọn ọ̀dọ́ ìpínlẹ̀ ọ̀sun fún ìpolongo ìbò 2027 ipò Gómìnà sáà kejì àbúrò bàbá rẹ̀ Ademola Adeleke.

ÀṢÀKẸ́ TV SHOW: Davido gba ìsinmi lenu isẹ orin kíkọ láti ṣáájú àwọn ọ̀dọ́ ìpínlẹ̀ ọ̀sun fún ìpolongo ìbò 2027…

Ka siwaju

Ẹ gé iléeṣẹ́ MTN àti DSTV South Africa, Sínetọ̀ Adams Oshiomhole rọ ìjọba pé kí ó yọ iléeṣẹ́ MTN, DSTV kúrò to jẹ́ ti South Africa àti ìwé àṣẹ wọn látàrí fífi ẹ̀mí ọmọ Nàìjíríà ṣòfò.

Sínetọ̀ Adams Oshiomhole rọ ìjọba pé kí ó yọ iléeṣẹ́ MTN, DSTV kúrò to jẹ́ ti South Africa àti ìwé…

Ka siwaju

Olórí Ọlọ́dẹ àti àwọn Aṣọ́gbó márùn-ún pàdánù ẹ̀mí wọn ni Kwara bí àwọn agbesunmobi ṣe yabo wọn, tí wọ́n sì dáná sún ọkọ̀ àti ọ̀kadà wọn.

Fọ́nrán àti àwòrán tó jáde síta ṣe àfihàn bí àwọn agbesunmobi ṣe dáná sún ọkọ̀ àti ọ̀kadà àwọn Aṣọ́gbó náà,…

Ka siwaju