Àjọ FAA ti ilẹ̀ Amẹ́ríkà ti gbé ìdènà kúrò lórí gbogbo àwọn ọkọ̀ òfurufú ní orílẹ̀-èdè náà, wọ́n sì sọ pé kò sí àmì kankan tó fi hàn pé ó jẹ́ ìkọlù nípasẹ̀ ẹ̀rọ ayélujára (cyberattack).

Àjọ FAA ti ilẹ̀ Amẹ́ríkà ti gbé ìdènà kúrò lórí gbogbo àwọn ọkọ̀ òfurufú ní orílẹ̀-èdè náà, wọ́n sì sọ…

Ka siwaju