Chris Pappas jẹ́ ọkùnrin àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ oníbálòpọ̀-kùnrin-sí-kùnrin (gay) ní gbangba nínú ìtàn Amẹrikà tí wọ́n dìbò yàn sínú Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà (Senate); ó sì dúpẹ́ lọ́wọ́ ọkọ rẹ̀.

Àwọn Ìdìbò ní Amẹ́ríkà: Chris Pappas kọ ìtàn gẹ́gẹ́ bí ọkùnrin àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ oníbálòpọ̀-kùnrin-sí-kùnrin (gay) ní gbangba tí…

Ka siwaju