Abdul El-Sayed di àgbà Aṣofin mùsùlùmí àkọ́kọ́ nínú ìtàn orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. El-sayed ṣẹ́gun Mike Rogers, olùdíje ẹgbẹ́ Republican tí Donald Trump ṣètìlẹ́yìn fún.

ÌRÒYÌN PÀTÀKÌ: Abdul El-Sayed ṣẹ́gun Mike Rogers, olùdíje ẹgbẹ́ Republican tí Donald Trump ṣètìlẹ́yìn fún, láti di Àgbà Aṣòfin (Senator)…

Ka siwaju