Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Zamfara ti mú ọmọ ẹgbẹ́ JIBWIS kan tó jẹ́ ọmọ ọdún méjìlélógún 22, nítorí fídíò kan tó ti tàn káàkiri, nínú èyí tí ó ti pe fún lílo ìbọn AK-47 láti pa àwọn Kristẹni ní Enugu àti Jos.

Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Zamfara ti mú ọmọ ẹgbẹ́ JIBWIS kan tó jẹ́ ọmọ ọdún méjìlélógún 22, nítorí fídíò kan…

Ka siwaju