Wọ́n mú ‘obìnrin ajẹ́hìn-ìhìn-rere’ kan láti Uganda, tó wá sí ìjọ Synagogue ní Nàìjíríà fún ìpolongo ìhìn-rere, lẹ́yìn tí wọ́n rí àpò kéékèèké kókéènì 87 nínú ẹ̀yà ara rẹ̀.

Wọ́n mú ‘obìnrin ajẹ́hìn-ìhìn-rere’ kan láti Uganda, tó wá sí ìjọ Synagogue ní Nàìjíríà fún ìpolongo ìhìn-rere, lẹ́yìn tí wọ́n…

Ka siwaju