Olùsọàgùntàn Pásítọ̀ Amos Isah tí wọ́n fi ẹ̀sùn kan pé ó fipa bá ọmọ ọdun mẹ́rìnlá lò pọ̀ nílé ìjọsìn Labuja, lọ ṣe àbẹ̀wò sí ìdílé ọmọ náà ní alẹ́ láti bẹ̀bẹ̀ fún ìdáríjì.

FÍDÍÒ ṣàfihàn Olusoagutan Amos Isah, ti wọn fẹ̀sùn kan pé o fipa bá ọmọ ọdun mẹ́rìnlá 14 yrs lò pọ̀…

Ka siwaju