Ẹ̀ka ọlọ́pàá ní FCT Abuja ti mú ọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ahmed Usman. Wọ́n fi ẹsùn kàn án pé ó fipá bá obìnrin kan tí ó jẹ́ òpó pẹ̀lú ọmọ ọwọ́ rẹ̀ lòpọ̀.

Ẹ̀ka ọlọ́pàá ní FCT ti mú ọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ahmed Usman. Wọ́n fi ẹsùn kàn án…

Ka siwaju