Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti kéde ọjọ́ ajé tíì ṣe ọjọ́ kọ̀ọ̀kandinlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà Ọdun 2026 yii ni ìdánwò junior WAEC yóò wáyé ní ìpínlẹ̀ náà.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti kéde ọjọ́ ajé tíì ṣe ọjọ́ kọ̀ọ̀kandinlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà Ọdun 2026 yii ni ìdánwò junior WAEC…

Ka siwaju

Jíjẹ oúnjẹ tòmátò tó bàjẹ́ àti ata eléyìí tí àwọn ènìyàn ń pè ní “ẹ̀ṣà tòmátò” lè fa àìsàn àrùn jẹjẹrẹ sí àgọ́ ara, ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ṣe ìkìlọ̀ àti àwọn onímọ̀ nípa oúnjẹ.

Àwọn tòmátò tí ó bàjẹ́ lè fa ikuna ara ènìyàn, àwọn onímọ̀ nípa oúnjẹ lo sọ bẹ́ẹ̀. Lẹ́yìn ìkìlọ̀ tí…

Ka siwaju