Olùsọàgùntàn Pásítọ̀ Amos Isah tí wọ́n fi ẹ̀sùn kan pé ó fipa bá ọmọ ọdun mẹ́rìnlá lò pọ̀ nílé ìjọsìn Labuja, lọ ṣe àbẹ̀wò sí ìdílé ọmọ náà ní alẹ́ láti bẹ̀bẹ̀ fún ìdáríjì.

FÍDÍÒ ṣàfihàn Olusoagutan Amos Isah, ti wọn fẹ̀sùn kan pé o fipa bá ọmọ ọdun mẹ́rìnlá 14 yrs lò pọ̀…

Ka siwaju

Iléeṣẹ́ ọmọ ogun Nàìjíríà ṣe ìkìlọ̀ fún àwọn ọmọ ogun Lodi si lílo ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ àwùjọ láti gbójú síta lórí ayélujára.

ÀṢÀKẸ́ TV SHOW: Iléeṣẹ́ ọmọogun Nàìjíríà ṣe ìkìlọ̀ fún àwọn ọmọ ogun Lodi si lilo ẹ̀rọ ibanisoro àwùjọ láti gbójú…

Ka siwaju