Bokoharam kéde pé àwọn fẹ́ ṣe ayẹyẹ ìparí ẹ̀kọ́ Al-Quran fún ọgọ́rùn-ún (100) nínú àwọn obìnrin àti àwọn ọmọ tí wọ́n jí gbé ní ìjọba Kaiama Kwara I to tí kẹ́kọ̀ọ́ yege ni àhámọ́ wọn.

Bokoharam kéde pé àwọn fẹ́ ṣe ayẹyẹ ìparí ẹ̀kọ́ Al-Quran fún ọgọ́rùn-ún (100) nínú àwọn obìnrin àti àwọn ọmọ tí…

Ka siwaju

Àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà ti mú Arábìnrin Kellu Abba ẹni àádọ́ta ọdún (50)ti won n so pe o má n kó oúnjẹ pẹ̀lú Hijabi lọ fún àwọn agbésùnmọ̀mí ní ìpínlẹ̀ Borno.

Àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà ti mú Arábìnrin Kellu Abba ẹni àádọ́ta ọdún (50)ti won n so pe o má n…

Ka siwaju