Àwọn ọmọ-ogun Nàìjíríà , àwọn oludije ti won yan láti ìpínlẹ̀ Imo lọ sí Zaria ni ìjàmbá ọkọ ojú -ọna, ọpọlọpọ àwọn ọmọ ogun lo farapa yánnayànna .

Awọn ọmọ-ogun Naijiria, awọn oludije ti o yan láti ìpínlẹ̀ Imo ni ijamba ọkọ oju-ọna ti o lọ si Zaria,…

Ka siwaju

Awọn Agbésùmọ́mí ṣe Ìkọlù sí eléso ààbò ìrù ẹkùn Sunday Igboho ní igbó Ọyọ àtijó National Park , ọpọlọpọ farapa yánnayànna.

Àwọn onijagidijagan Agbésùmọ́mí ṣe Ìkọlù sí eléso irú ẹkùn Sunday Igboho’s ní igbo Ọyọ àtijó National Park , ọpọlọpọ farapa…

Ka siwaju