NYSC lè awọn ọmọ ẹgbẹ àgùnbánirọ̀ Corps kuro ni ìjọba Kaiama LGA Kwara nítorí ìbẹ̀rù bojo àwọn Bokoharam ń gbèrò láti ṣe ìkọlù tuntun mìíràn sí agbègbè náà.

Lónìí tíì ṣe ọjọ́ ajé ọjọ́ ìkíni oṣù Kàrún ọdún 2026 yii, ní NYSC lè awọn ọmọ ẹgbẹ àgùnbánirọ̀ Corps…

Ka siwaju