ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ Ọba onípele tí ipele Ọ̀wọ̀ ń dunkoko ikú mọ́ ọmọbìnrin ọdún mọ́kànlélógún (21yrs),Látàrí bí Kehinde ṣe sọ pé ọba lo fún òun lóyún tí ọba sì ní kí òun ló yọ oyún náà, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, òun yóò fi ikú ṣe ifá jẹ́. Asake Apr 18, 2026 6 Ọba onípele tí ipele ni ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀wọ́ Ondo ń dunkoko ikú mọ́ ọmọ ọdún mọ́kànlélógún (21yrs) tí orúkọ rẹ… Ka siwaju