Ọ̀gá ọlọ́pàá Tunji Disu ń wá àjọṣepọ̀ ìfọwọ́sowopọ̀ àwọn ọlọ́pàá àti àwọn ará ìlú ní gbogbo agbègbè láti ní ètò ààbò tó péye nínú Nàìjíríà.

Ọ̀gá ọlọ́pàá Tunji Disu, n wá , ajọṣepọ ìfọwọ́sowopo àwọn ọlọ́pàá àti àwọn ará ìlú agbègbè láti ni ètò ààbò…

Ka siwaju

Àwọn agbébọn pa Dasola Sanusi òṣìṣẹ́birin ẹlẹ́ṣọ àbò “Man O war ” ni òpópónà Ìbàdàn – Ago Iwoye ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Àwọn agbébọn pa Dasola Sanusi òṣìṣẹ́birin ẹlẹ́ṣọ àbò “ManO war” ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Àwọn afurasí agbébọn ajinigbe tí pa òṣìṣẹ́birin…

Ka siwaju