Ayẹyẹ Ọjọ àyájọ́ Awọn ọmọde àti EID tí ọdún ileya yìí : Gomina Ọyọ ṣe àdéhùn idaniloju pé awọn ọmọ ile-iwe ti wọn ji àti awọn olukọ ni igbiyanju ìtúsílẹ̀ wọn ti nlọ lọwọ.

Ayẹyẹ Ọjọ àyájọ́ Awọn ọmọde àti EID tí ọdún ileya yìí : Gomina Ọyọ ṣe àdéhùn idaniloju pé awọn ọmọ…

Ka siwaju

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí fi Lẹ́tà ránṣẹ́ dúnkokò mọ́ àwọn ilé ìwé ni ijoba ìbílè Odeda ni ìpínlẹ̀ Ogun, pé àwọn ń bọ̀ láti jí wọn gbé , àwọn ọdẹ àdúgbò pariwo síta

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí fi Lẹ́tà ránṣẹ́ dúnkokò mọ́ àwọn ilé ìwé ni ijoba ìbílè Odeda ni ìpínlẹ̀ Ogun, pé àwọn ń…

Ka siwaju

Ààrẹ ìgbìmọ̀ Yorùbá council bu ẹnu àtẹ́ lu ìkọlù tí àwọn agbésùnmọ̀mí afẹ̀míṣòfò ṣe sí ilé ẹ̀kọ́ ni Ọ̀yọ́, ó sì ké sí àpérò gbogbo àwọn Lobaloba nílẹ̀ Yorùbá .

ÀṢÀKẸ́ TV SHOW: Ààrẹ ìgbìmọ̀ Yorùbá council bu ẹnu àtẹ́ lu ìkọlù tí àwọn agbésùnmọ̀mí afẹ̀míṣòfò ṣe sí ilé ẹ̀kọ́…

Ka siwaju

Gómìnà Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ Seyi Makinde sọ pé àwọn ẹlẹ́ṣọ àbò tí mú ó kéré tán mẹ́fà nínú àwọn agbésùnmọ̀mí bokoharam tó ṣe ìkọlù sí àwọn ilé ìwé mẹta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní ìjọba ìbílẹ̀ Oriire ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ Seyi Makinde sọ pé àwọn ẹlẹ́ṣọ àbò tí mú ó kéré tán mẹ́fà nínú àwọn agbésùnmọ̀mí bokoharam…

Ka siwaju

Seyi Makinde ṣe ifilọ́lẹ̀ àti fifisílẹ̀ ọ́fíìsí Ẹ̀ka ẹ̀ṣọ́ ààbò tuntun láti kojú àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ̀mí ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ .

Ní kùtùkùtù òní tíì ṣe ọjọ́ Abameta ọjọ́ keridinlogun oṣù Kàrún ọdún 2026 ni Seyi Makinde ṣe ifilọlẹ ati fifisilẹ…

Ka siwaju

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí ṣe ìkọlù sí Ilé ìwé mẹta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní Ọ̀yọ́:ilé ìwé Baptist Nursery and Primary school, Community Grammar School Esiele àti L. A Primary school, wọn pa Olukọni, jí ọ̀gá àgbà àti ọ̀pọ̀ àwọn ọmọ ilé ìwé gbé lọ.

Awọn Agbéṣùmọ̀mí ṣe ìkọlù sí ile-iwe mẹta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ , wọ́n pa Olukọni,wọn ji Awọn ọmọ ile-iwe ati…

Ka siwaju

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí ti jí ọ̀gá àgbà iléèwé àti àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ gbé lọ, ní ilé ìwé gírámà Ahoro – Esinele ní ìjọba ìbílẹ̀ Oriire ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.

Awọn Agbéṣùmọ̀mí ti ji ọ̀gá àgbà ilé ìwé ,àti àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gbé lọ nilu Ahoro-Esinele ní ìjọba ìbílẹ̀ Oriire ìpínlẹ̀…

Ka siwaju