ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ Olùsọàgùntàn Pásítọ̀ Amos Isah tí wọ́n fi ẹ̀sùn kan pé ó fipa bá ọmọ ọdun mẹ́rìnlá lò pọ̀ nílé ìjọsìn Labuja, lọ ṣe àbẹ̀wò sí ìdílé ọmọ náà ní alẹ́ láti bẹ̀bẹ̀ fún ìdáríjì. Asake May 13, 2026 0 FÍDÍÒ ṣàfihàn Olusoagutan Amos Isah, ti wọn fẹ̀sùn kan pé o fipa bá ọmọ ọdun mẹ́rìnlá 14 yrs lò pọ̀… Ka siwaju