Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá Nàìjíríà tí tu ibùdó àwọn Ẹgbẹ ti n ta ènìyàn, fi ọmọ ènìyàn ṣe owó ẹrú káàkiri Nàìjíríà ká , wọn gba àwọn ọmọ ara ilẹ̀ òkèèrè 30 là Ni Abuja àti ní Nasarawa.

Ọlọ́pàá náà sọ pe iwadii bẹ̀rẹ̀ lẹ́hìn àwọn ijabọ oye ti fi ipadanu ti ọpọlọpọ àwọn ọmọ ìlú òkèèrè láàrin…

Ka siwaju