Gómìnà Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ Seyi Makinde ni àárọ̀ òní tíì ṣe ọjọ́ Àbámẹ́ta, Ọgbọ̀n ọjọ́ Oṣù Kàrún 2026, kó Ọgọọgọrun àwọn ọkọ̀ ayọkẹlẹ tí ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn irinṣẹ ìbániẹnisọ̀rọ̀ fún àwọn ilé isẹ ààbò ni ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ pẹ̀lú àwọn ọlọ́pàá.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ Seyi Makinde ni àárọ̀ òní tíì ṣe ọjọ́ Àbámẹ́ta, Ọgbọ̀n ọjọ́ Oṣù Kàrún 2026, kó Ọgọọgọrun àwọn…

Ka siwaju

Ìjọba Nàìjíríà ti mú 327 àwọn Awakùsà tó ń wa kùṣà lọ́nà tí kò bófin mú, pẹ̀lú àwọn afurasí àjèjì ọmọ ilẹ̀ òkèèrè tó ń lo àwọn agbésùnmọ̀mí láti wa kùṣà nínú Nàìjíríà.

ÀṢÀKẸ́ TV NEWS : Ìjọba Nàìjíríà ti Mu 327 Àwọn Awakùsà tó ń wa kùṣà lọ́nà tí kò bófin mú…

Ka siwaju

Ààrẹ Tinubu rán gbákejì rẹ̀ Kashim Shettima lọ sí Ondo fún ti ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọgọ́rùn-ún ọdún DR. Reuben Fasoranti.

Igbákejì Ààrẹ Nàìjíríà Kashim Shettima dé sí Ondo fún ti ayẹyẹ ọgọ́rùn-ún ọdún ọjọ́ ìbí Reuben Fasoranti. Igbákejì orílẹ̀ èdè…

Ka siwaju

Ààrẹ Tinubu ti yan Ìyà àárín Arinola Ogbara Banjoko gẹ́gẹ́ bí Alákóso aṣojú lórí ìgbìmò ìṣòwò pàsí pààrọ̀ ọjà ìpínlẹ̀ Èkó.

Ààrẹ Tinubu ti yan Ìyà àárín Arinola Ogbara Banjoko gẹ́gẹ́ bí Alákóso aṣojú lórí ìgbìmò ìṣòwò pàsí pààrọ̀ ọjà ìpínlẹ̀…

Ka siwaju