Àwọn Agbéṣùmọ̀mí yawọ ìlú Rafiu Ajakaye olórí àwọn akọ̀ròyìn fún Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara.Wón jí ènìyàn mọ́kànlá gbé lọ nínú ilé rẹ̀ ìjọba ìbílẹ̀ Ifelodun Kwara.

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí yawọ ìlú Rafiu Ajakaye olórí àwọn oníròyìn fún Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara.Wón jí ènìyàn mọ́kànlá gbé lọ nínú ìlú…

Ka siwaju

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí jí arabinrin kan Olanike Ogundare gbé lọ nínú ilé rẹ ní ìpínlẹ̀ Èkó.Wọn kí àwọn ẹbí rẹ san N60Millionu owó ìtúsílẹ̀ rẹ.

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí jí arabinrin kan gbé lọ nínú ilé rẹ L’eko, lẹ́yìn ti wọ́n borí àwọn ẹlẹ́ṣọ àbò agbègbè náà…

Ka siwaju

Ààrẹ Tinubu buwọ́lu N17bilionu láti ṣe àtìlẹyìn ìdàgbàsókè ìpínlẹ̀,àti àwọn agbègbè ìsèlù 8,804 gbogbo orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

Aarẹ Bola Tinubu ti buwọ́lu ₦17 bilionu tí Awujọ-orisun inawo iṣe awujọ ti Orilẹ-ede Nàìjíríà lati ṣe atilẹyin idagbasoke ìpínlẹ̀…

Ka siwaju

Ọwọ́ iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Èkó ti tẹ ọlọ́pàá tó n gba owó rìbá lọ́wọ́ àwọn awakọ̀, onikẹ̀kẹ́ maruwa, ọlọ́kadà ní Idimu L’eko.

Ọwọ́ Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Èkó ti tẹ ọlọ́pàá 👮👮‍♂️ tó ń gba rìbá lọ́wọ́ àwọn oni Kẹ̀kẹ́nape ,awakọ̀,ọlọ́kadà ,🚴‍♂️ onímaruwa…

Ka siwaju