Skip to content
  • Tuesday, 30 June 2026
  • 3:30 pm
  • Tẹle wa
ÀṢÀKẸ́ NEWS
  • Ile
  • ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ
  • ÌṢÈLÚ
  • Ere Idaraya
  • ÌGBÉSÍ AYÉ
  • ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
  • Ẹ̀KỌ́ ÈDÈ YORÙBÁ
  • Home
  • 2026
  • April
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Ìjọba ní kò sí owó ìtúsílẹ̀ kan tí àwọn fẹ́ san fún àwọn agbésùnmọ̀mí fún obìnrin, ọmọdé 416 tó wà ní àhámọ́ wọn.

Asake Apr 22, 2026 0

A kò ní owó ìtúsílẹ̀ kan tí a fẹ́ san fún àwọn agbésùnmọ̀mí fún obìnrin, ọmọdé 416 tó wà ní…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Àwọn agbébọn pa Dasola Sanusi òṣìṣẹ́birin ẹlẹ́ṣọ àbò “Man O war ” ni òpópónà Ìbàdàn – Ago Iwoye ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Asake Apr 22, 2026 0

Àwọn agbébọn pa Dasola Sanusi òṣìṣẹ́birin ẹlẹ́ṣọ àbò “ManO war” ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Àwọn afurasí agbébọn ajinigbe tí pa òṣìṣẹ́birin…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ

Ìyá àti ọmọ rẹ̀ ọkùnrin pàdánù ẹ̀mí wọn bí wọn ṣe n rin ìrìn àjò lọ sí ilẹ̀ mímọ́ Mecca.

Asake Apr 22, 2026 0

Àwọn Àjọ tó ń ṣe agbeteru ìrìnàjò lọ sí ilẹ̀ mímọ́ Mecca tí ìpínlẹ̀ Kano pilgrim tí kẹ́dùn ìyá àti…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ

Ẹ yọ Bello Matawalle Nípò – Asojú sofin L’ámẹ́ríkà

Asake Apr 21, 2026 3

Ọ̀kan lára àwọn asoju asofin Amẹ́ríkà arábìnrin Kimberly Daniel fi ẹ̀sùn kan Gómìnà Ìpínlẹ̀ Zamfara tẹ́lẹ̀ rí, Bello Matawalle pé…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara Abdrahman kéde pé òun yóò san N20milionu fún ẹnì kọ̀ọ̀kan àwọn ológun mẹta tí àwọn agbésùnmọ̀mí pa ni ọgbà ológun kemanji Kwara.

Asake Apr 21, 2026 0

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara Abdrahman tí ṣe ìpinnu pé òun yóò san N20m fún ẹnì kọ̀ọ̀kan àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà mẹta…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ

Trump sọ pé Amẹ́ríkà ti dá ọkọ̀ ojú omi tó ń gbé ẹ̀bùn lọ fún Orílẹ̀ èdè Iran dúró .

Asake Apr 21, 2026 0

Ààrẹ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà Donald Trump ni àwọn ọmọ ogun Amẹ́ríkà ti dá ọkọ̀ ojú omi China ti o n…

Ka siwaju
ÌṢÈLÚ

Àwọn jàǹdùkú lẹ́yìn olóṣèlú na alága ìjọba ìbílẹ̀ Ọ̀wọ̀, wọ́n na à nà já létí, wọ́n na gba Sokoto nìdí rẹ̀.

Asake Apr 21, 2026 0

Bí àwọn jàǹdùkú lẹ́yìn olóṣèlú ṣe yinbon sókè gbogbo ará ìlú ń sá kiri,ti gbogbo agbègbè náà sì dabi tí…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí pa àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà mẹrin jí ọ̀pọ̀ ará ìlú gbé lọ, ni ọgbà ológun kemanji Kwara.

Asake Apr 20, 2026 0

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí da ìbọn bolẹ̀ yawọ ọgbà àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà tó wà ní kemanji ni ijoba ìbílẹ̀ kaiama Kwara,…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

A kò fi ìwé pé Sultan Sokoto síbi ayẹyẹ ibi tí a ti fẹ́ ṣí pápákọ̀ òfuurufú Chapel tuntun ní Fct Labuja -CAN

Asake Apr 19, 2026 3

Àpapọ̀ aṣojú ẹlẹ́sìn Kìrìsìtẹ́nì(CAN) sọ pé àwọn kò fi ìwé pé Sultan Sokoto Sa’ad Abubakar, láti wá ṣe bí adarí…

Ka siwaju
ÌGBÉSÍ AYÉ Uncategorized

Lebanon yẹ àdéhùn jógunómí ọlọ́sẹ̀ méjì, wọ́n ju àdó olóró sí Israel.

Asake Apr 19, 2026 1

Àlàyé tí Netanyahu ṣe rèé lórí àdéhùn jógunómí tó wà láàrin Israeli àti Lebanon Àdéhùn jógunómí yìí bá ọ̀pọ̀ ọmọ…

Ka siwaju

Posts pagination

1 2 3 4 … 6

Iroyin aipẹ

  • Orúkọ 104 àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà ni kíkùn ni Iléeṣẹ́ ológun kọ síta pé wọ́n pàdánù pẹ̀lú àwọn ìbọn iṣẹ wọn ọ̀sé kan lẹ́hìn ìkọlù ti Boko Haram ṣe sí Ibùdó ológun Borno.
  • Iléeṣẹ́ ológun ọmọ Nàìjíríà kéde pe 104 ọmọ ogun ni won padanu ni ọsẹ kan lẹhin ikọlu ńlá ti Boko Haram ṣe sí Ibùdó ológun Borno.
  • Àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà tí operations Hadin Kai (OPHK) tí ṣe àṣeyọrí gba àwọn ọmọ ilé ìwé mẹ́wàá tó ń ṣe ìdánwò Neco àti àwọn olùkọ́ tí wọ́n jí gbé sílẹ̀.
  • Àwọn agbésùmọ́mí ti dé ẹnu-ọ̀nà mi-Enoch Adeboye Olùdásílẹ̀ ìjọ Redeem sọ̀rọ̀.
  • Àwọn ọlọ́pàá orílẹ̀ èdè Nàìjíríà fidi rẹ mulẹ pé àwọn Boko Haram ti jí àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ to ń kọ ìdánwò Neco gbe lọ ,tí wọ́n sì pa awọn olùkọ́ nínú ìkọlù tó wáyé ní Borno.
Iroyin to Nlo
Orúkọ 104 àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà ni kíkùn ni Iléeṣẹ́ ológun kọ síta pé wọ́n pàdánù pẹ̀lú àwọn ìbọn iṣẹ wọn ọ̀sé kan lẹ́hìn ìkọlù ti Boko Haram ṣe sí Ibùdó ológun Borno.
Jun 30, 2026
Iléeṣẹ́ ológun ọmọ Nàìjíríà kéde pe 104 ọmọ ogun ni won padanu ni ọsẹ kan lẹhin ikọlu ńlá ti Boko Haram ṣe sí Ibùdó ológun Borno.
Jun 30, 2026
Àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà tí operations Hadin Kai (OPHK) tí ṣe àṣeyọrí gba àwọn ọmọ ilé ìwé mẹ́wàá tó ń ṣe ìdánwò Neco àti àwọn olùkọ́ tí wọ́n jí gbé sílẹ̀.
Jun 30, 2026
Àwọn agbésùmọ́mí ti dé ẹnu-ọ̀nà mi-Enoch Adeboye Olùdásílẹ̀ ìjọ Redeem sọ̀rọ̀.
Jun 29, 2026
Àwọn ọlọ́pàá orílẹ̀ èdè Nàìjíríà fidi rẹ mulẹ pé àwọn Boko Haram ti jí àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ to ń kọ ìdánwò Neco gbe lọ ,tí wọ́n sì pa awọn olùkọ́ nínú ìkọlù tó wáyé ní Borno.
Jun 29, 2026

Asọye aipẹ

  1. Katie1486 on Ìpayà bí iná ṣe jó ilé ìtajà ike tó wà ni old garage Osogbo tó jẹ́ olú ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀sun.
  2. Hello from [your-website] on Bokoharam kéde pé àwọn fẹ́ ṣe ayẹyẹ ìparí ẹ̀kọ́ Al-Quran fún ọgọ́rùn-ún (100) nínú àwọn obìnrin àti àwọn ọmọ tí wọ́n jí gbé ní ìjọba Kaiama Kwara I to tí kẹ́kọ̀ọ́ yege ni àhámọ́ wọn.
  3. Asake on Ìjọba àpapọ̀ tí kó orúkọ àwọn ọmọ Nàìjíríà síta ,Tukur Mamu, Simon Njoku Ekpa, IPOB, àti àwọn gúrúpù12 mìíràn, tó ń ṣe ìrànlọ́wọ́ àti àtìlẹyìn fún àwọn agbésùnmọ̀mí.
  4. Asake on Ọwọ́ iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Èkó ti tẹ ọlọ́pàá tó n gba owó rìbá lọ́wọ́ àwọn awakọ̀, onikẹ̀kẹ́ maruwa, ọlọ́kadà ní Idimu L’eko.
  5. Asake on Ààrẹ Tinubu buwọ́lu N17bilionu láti ṣe àtìlẹyìn ìdàgbàsókè ìpínlẹ̀,àti àwọn agbègbè ìsèlù 8,804 gbogbo orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
Awọn ẹka
  • ÀWỌN ÌRÒYÌN TÍ Ó NÍPA
  • ÌGBÉSÍ AYÉ
  • ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
  • ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ
  • ÌṢÈLÚ
  • Uncategorized
Iroyin ti oti le Ti padanu
News Mart logo

Ni pa wa

Shagam
info@asakenews.com
+212 710-380820
Iroyin Tuntun
Orúkọ 104 àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà ni kíkùn ni Iléeṣẹ́ ológun kọ síta pé wọ́n pàdánù pẹ̀lú àwọn ìbọn iṣẹ wọn ọ̀sé kan lẹ́hìn ìkọlù ti Boko Haram ṣe sí Ibùdó ológun Borno.
Jun 30, 2026
Iléeṣẹ́ ológun ọmọ Nàìjíríà kéde pe 104 ọmọ ogun ni won padanu ni ọsẹ kan lẹhin ikọlu ńlá ti Boko Haram ṣe sí Ibùdó ológun Borno.
Jun 30, 2026
Àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà tí operations Hadin Kai (OPHK) tí ṣe àṣeyọrí gba àwọn ọmọ ilé ìwé mẹ́wàá tó ń ṣe ìdánwò Neco àti àwọn olùkọ́ tí wọ́n jí gbé sílẹ̀.
Jun 30, 2026
Àwọn agbésùmọ́mí ti dé ẹnu-ọ̀nà mi-Enoch Adeboye Olùdásílẹ̀ ìjọ Redeem sọ̀rọ̀.
Jun 29, 2026
Àwọn ọlọ́pàá orílẹ̀ èdè Nàìjíríà fidi rẹ mulẹ pé àwọn Boko Haram ti jí àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ to ń kọ ìdánwò Neco gbe lọ ,tí wọ́n sì pa awọn olùkọ́ nínú ìkọlù tó wáyé ní Borno.
Jun 29, 2026
Awọn ẹka
  • ÀWỌN ÌRÒYÌN TÍ Ó NÍPA
  • ÌGBÉSÍ AYÉ
  • ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
  • ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ
  • ÌṢÈLÚ
  • Uncategorized
Forukọsilẹ Fun Iwe Iroyin Wa

Se alabapin si iwe iroyin wa lati gba awọn nkan tuntun wa lesekese!

Copyright © 2026 Asake News | Design by Yaagboyaaju Tech

  • Home
  • About
  • Blog
  • Contact