Skip to content
  • Sunday, 16 August 2026
  • 7:25 pm
  • Tẹle wa
ÀṢÀKẸ́ NEWS
  • Ile
  • ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ
  • ÌṢÈLÚ
  • Ere Idaraya
  • ÌGBÉSÍ AYÉ
  • ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
  • Ẹ̀KỌ́ ÈDÈ YORÙBÁ
  • Home
  • 2026
  • June
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Àwọn agbésùmọ́mí kọ́ ló wà nínú fọ́nrán tí ara ìlú ń gbé kiri lórí ayélujára àwọn ọdẹ figilantes ní – Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Nàìjíríà takò fọ́nrán náà.

Asake Jun 25, 2026 0

Àwọn agbésùmọ́mí kọ́ ló wà nínú fọ́nrán tí ara ìlú ń gbé kiri lórí ayélujára àwọn ọdẹ figilantes ní –…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Àwọn jàǹdùnkú olóṣèlú pa olórí ọ̀dọ́ ẹgbẹ Accord Esa-Oke Ọ̀sun, Gómìnà Adeleke pé Komisona ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ọ̀sun Wole Oke, Oyetola, Oyebamiji àti àwọn mìíràn fún apero, ṣe abewo sí àwọn ẹbí .

Asake Jun 24, 2026 0

Gomina Adeleke pe Komisana olopaa, Wole Oke, Oyetola, Oyebamiji, ati awon mi-in nitori ipaniyan òṣèlú ìpínlẹ̀ Ọ̀sun Gomina Ademola Adeleke…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Ilé-igbimọ aṣojú sòfin àgbà L’abuja ti ṣe àtúnṣe ikẹhin òfin lati fi idi ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ ni Nàìjíríà múlẹ̀.wọn bẹ̀rẹ̀ Jomitoro ọ̀rọ̀ lórí owó ọlọ́pàá ìpínlẹ̀.

Asake Jun 24, 2026 0

Ilé ìgbìmò aṣojú sòfin àgbà L’abuja bẹrẹ Jomitoro ọ̀rọ̀ lórí owó ọlọ́pàá ìpínlẹ̀. Àwọn ilé ìgbìmọ̀ asoju asofin Labuja tí…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà ikọ̀ Fansan Yamma ni òkè ọya tí gba àwọn ará ìlú tí wọ́n jí gbé, wọn gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun ìjà olóró padà.

Asake Jun 24, 2026 0

Àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà ikọ̀ Fansan Yamma ni òkè ọya tí gba àwọn ará ìlú tí wọ́n jí gbé, wọn…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ

Awọn ọmọ Naijiria tó wà nínú atimọle ní orílẹ̀ èdè India tí ké gbàjarè síta, fi ẹ̀sùn kan Ile-iṣẹ ọlọ́pàá pé wọ́n tí Kọ wọn silẹ, Sọ pe O kéré tán 400 ọmọ Nàìjíríà ló wà nínú àhámọ́ ní Ibùdó Deportation.

Asake Jun 24, 2026 0

Awọn ọmọ Naijiria tó wà nínú atimọle ní orílẹ̀ èdè India fi ẹ̀sùn kan Ile-iṣẹ ọlọ́pàá pé wọ́n tí Kọ…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tí kéde isede òfin konile gbele òní -wákàtí mẹ́rìndínlógún (16hrs) ni agbègbè Ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́wàá 10.

Asake Jun 24, 2026 0

Ijoba Oyo kéde isede òfin konile gbele òní -wákàtí mẹ́rìndínlógún (16hrs) ni gbogbo agbègbè Ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́wàá 10. Oṣu Kẹfa…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Sowore so wipe won ti gbe awon omo ile iwe Oyo ti won ji gbe lo si Kaduna, ó ní àwọn ajo DSS se fi ìtúsílẹ̀ wọ́n sílẹ̀ , wọ́n yọ ẹnu sí àwọn alariwisi ti ìjọba Tinubu.

Asake Jun 23, 2026 0

Sowore so wipe won ti gbe awon omo ile iwe Oyo ti won ji gbe lo si Kaduna, ó ní…

Ka siwaju
ÌṢÈLÚ

Awọn oṣiṣẹ DSS ji Sowore j ni ile ẹjọ Abuja leyin ti adajọ ti paṣẹ pe ki wọn fi ẹwọn Kuje silẹ.

Asake Jun 22, 2026 0

Awọn oṣiṣẹ DSS ji Sowore j ni ile ẹjọ Abuja leyin ti adajọ ti paṣẹ pe ki wọn fi ẹwọn…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ

‘Emi Ko Ni Dariji Rẹ Laelae’: Aṣofin Ilu Gẹẹsi bu ‘itiju’ Starmer Lẹhin ti Alakoso fi ipo silẹ.

Asake Jun 22, 2026 0

‘Emi Ko Ni Dariji Rẹ Laelae’: Aṣofin Ilu Gẹẹsi bu ‘itiju’ Starmer Lẹhin ti Alakoso fi ipo silẹ Starmer fi…

Ka siwaju
ÌṢÈLÚ

Àwọn jàǹdùnkú olóṣèlú yìnbon pa Ọ̀dọ́mọdékùnrin Ezekiel Olapade ẹni ọdun mẹ́rìnlá ,tí ẹlòmíràn si farapa yánnayànna lágbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Irepodun n’ilu Ilobu ìpínlẹ̀ Ọ̀sun.

Asake Jun 22, 2026 0

Àwọn jàǹdùnkú olóṣèlú yìnbon pa Ọ̀dọ́mọdékùnrin,tí ẹlòmíràn si farapa yánnayànna lágbègbè LG Secretariat ní Ọ̀sun. Rògbòdìyàn ṣẹlẹ̀ nítòsí ẹnu ọ́nà…

Ka siwaju

Posts pagination

1 2 3 4 … 10

Iroyin aipẹ

  • Ìdìbò ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Obìnrin oníwà-ipá jàǹdùnkú olóṣèlú kan tí wọ́n ń pè ní ‘Arugba’ halẹ̀ mọ́ àwọn olùdìbò pé òun yóò gé ìka ọwọ́ wọn tí wọn kò bá dìbò fún ẹgbẹ́ APC.
  • Ikọlu sí Agbẹnusọ Ile-igbimọ Ipinle Osun: Afurasi jẹwọ pe oludije ẹgbẹ APC, Eniade, lo gba oun láti pa a, o si tun jẹwọ pe oun yin ibọn lẹẹmeji.
  • Amnesty International tún rọ àwọn aláṣẹ ní Nàìjíríà láti bọ̀wọ̀ fún àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ-ìlú nígbà ìdìbò Gómìnà ní ìpínlẹ̀ Osun.
  • Ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Àwọn ọlọ́pàá pe Sẹ́nátọ̀ Fadahunsi ti ẹgbẹ́ APC wá fún ìbéèrè lórí ọ̀rọ̀ ìhalẹ̀ láti pa àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Accord.
  • Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Adeleke, fi ẹ̀sùn kan àwọn ọlọ́pàá pé wọ́n ní ètò láti mú àwọn aṣáájú ẹgbẹ́ òṣèlú Accord kí wọ́n sì fi wọ́n sẹ́wọ̀n ní Abuja títí tí ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun yóò fi parí.
Iroyin to Nlo
Ìdìbò ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Obìnrin oníwà-ipá jàǹdùnkú olóṣèlú kan tí wọ́n ń pè ní ‘Arugba’ halẹ̀ mọ́ àwọn olùdìbò pé òun yóò gé ìka ọwọ́ wọn tí wọn kò bá dìbò fún ẹgbẹ́ APC.
Aug 13, 2026
Ikọlu sí Agbẹnusọ Ile-igbimọ Ipinle Osun: Afurasi jẹwọ pe oludije ẹgbẹ APC, Eniade, lo gba oun láti pa a, o si tun jẹwọ pe oun yin ibọn lẹẹmeji.
Aug 13, 2026
Amnesty International tún rọ àwọn aláṣẹ ní Nàìjíríà láti bọ̀wọ̀ fún àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ-ìlú nígbà ìdìbò Gómìnà ní ìpínlẹ̀ Osun.
Aug 12, 2026
Ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Àwọn ọlọ́pàá pe Sẹ́nátọ̀ Fadahunsi ti ẹgbẹ́ APC wá fún ìbéèrè lórí ọ̀rọ̀ ìhalẹ̀ láti pa àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Accord.
Aug 12, 2026
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Adeleke, fi ẹ̀sùn kan àwọn ọlọ́pàá pé wọ́n ní ètò láti mú àwọn aṣáájú ẹgbẹ́ òṣèlú Accord kí wọ́n sì fi wọ́n sẹ́wọ̀n ní Abuja títí tí ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun yóò fi parí.
Aug 12, 2026

Asọye aipẹ

  1. ABDULRASAQ ADENIYI SOLIU on Àwọn ọkùnrin mẹ́jọ tí ọjọ́ orí wọn wà láàárín ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún sì méjìlélọ́gbọ̀n ni wọ́n fi ẹ̀sùn kàn lórí ètò láti kọlu ayẹyẹ UFC ti Trump ní Ilé Ààrẹ ni White House.
  2. Lewishow on Ìpayà bí iná ṣe jó ilé ìtajà ike tó wà ni old garage Osogbo tó jẹ́ olú ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀sun.
  3. Timsothyemeri on Ìpayà bí iná ṣe jó ilé ìtajà ike tó wà ni old garage Osogbo tó jẹ́ olú ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀sun.
  4. OLUFEMI OSHIKPOYA on Wọn pa ènìyàn kan, ọpọlọpọ farapa yannayanna bí Ẹgbẹ́ òṣèlú APC àti Accord Party ṣe ja ni Osogbo.
  5. Alma1848 on Ọwọ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ẹdo tẹ afurasí ajínigbé méjì, wọn gba ara ènìyàn tó ti jẹrà méjì padà.
Awọn ẹka
  • ÀWỌN ÌRÒYÌN TÍ Ó NÍPA
  • Ere Idaraya
  • ÌGBÉSÍ AYÉ
  • ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
  • ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ
  • ÌṢÈLÚ
  • Uncategorized
Iroyin ti oti le Ti padanu
News Mart logo

Ni pa wa

Shagam
info@asakenews.com
+212 710-380820
Iroyin Tuntun
Ìdìbò ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Obìnrin oníwà-ipá jàǹdùnkú olóṣèlú kan tí wọ́n ń pè ní ‘Arugba’ halẹ̀ mọ́ àwọn olùdìbò pé òun yóò gé ìka ọwọ́ wọn tí wọn kò bá dìbò fún ẹgbẹ́ APC.
Aug 13, 2026
Ikọlu sí Agbẹnusọ Ile-igbimọ Ipinle Osun: Afurasi jẹwọ pe oludije ẹgbẹ APC, Eniade, lo gba oun láti pa a, o si tun jẹwọ pe oun yin ibọn lẹẹmeji.
Aug 13, 2026
Amnesty International tún rọ àwọn aláṣẹ ní Nàìjíríà láti bọ̀wọ̀ fún àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ-ìlú nígbà ìdìbò Gómìnà ní ìpínlẹ̀ Osun.
Aug 12, 2026
Ìdìbò Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun: Àwọn ọlọ́pàá pe Sẹ́nátọ̀ Fadahunsi ti ẹgbẹ́ APC wá fún ìbéèrè lórí ọ̀rọ̀ ìhalẹ̀ láti pa àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Accord.
Aug 12, 2026
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Adeleke, fi ẹ̀sùn kan àwọn ọlọ́pàá pé wọ́n ní ètò láti mú àwọn aṣáájú ẹgbẹ́ òṣèlú Accord kí wọ́n sì fi wọ́n sẹ́wọ̀n ní Abuja títí tí ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun yóò fi parí.
Aug 12, 2026
Awọn ẹka
  • ÀWỌN ÌRÒYÌN TÍ Ó NÍPA
  • Ere Idaraya
  • ÌGBÉSÍ AYÉ
  • ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
  • ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ
  • ÌṢÈLÚ
  • Uncategorized
Forukọsilẹ Fun Iwe Iroyin Wa

Se alabapin si iwe iroyin wa lati gba awọn nkan tuntun wa lesekese!

Copyright © 2026 Asake News | Design by Yaagboyaaju Tech

  • Home
  • About
  • Blog
  • Contact