Olórí Bandit Turji Bello sọ pé òun ló ṣe ikọlu sí àwọn oṣiṣẹ eléso ààbò ọmọ ogun Nàìjíríà ni Zamfara, Sokoto nínú fídíò tuntun tó gbé síta.

Olórí Bandit Turji Bello sọ pé òun ló ṣe ikọlu sí àwọn oṣiṣẹ eléso ààbò ọmọ ogun Nàìjíríà ni Zamfara,…

Ka siwaju

Ọlọ́pàá Ọ̀yọ́ àti alága ìjọba ìbílẹ̀ Oorelope ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti tako ipa tí Sunday Igboho kó nípa ìtúsílẹ̀ àwọn ènìyàn olufaragba tí àwọn agbésùmọ́mí jí gbé.

Ọlọ́pàá Ọ̀yọ́ àti alága ìjọba ìbílẹ̀ Oorelope ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tako Ipa Sunday Igboho nínú ìtúsílẹ̀ Àwọn ènìyàn tí fúlàní agbésùnmọ̀mí…

Ka siwaju

Ilé-ẹjọ́ gíga ti ìjọba àpapọ̀ ni ilu Abuja ti dajọ ikú fún Zakaria Garba, ẹni ọdun 37 latari bí ó…

Ka siwaju

Remi Tinubu ṣayẹyẹ ẹ̀jẹ̀ lágbàáyé àwọn oluranlọwọ dídá ẹ̀jẹ̀ jọ fún àwọn aláìsàn,ó rọ awọn ọmọ Nàìjíríà lati ran àwọn aláìsàn lọ́wọ́ nípa ẹ̀jẹ̀ gba ẹbun atinuwa

Remi Tinubu ṣayẹyẹ ẹ̀jẹ̀ lágbàáyé àwọn oluranlọwọ dídá ẹ̀jẹ̀ jọ fún àwọn aláìsàn,ó rọ awọn ọmọ Nàìjíríà lati ran àwọn…

Ka siwaju

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkìtì ti kéde ìsinmi lenu isẹ fún àwọn òṣìṣẹ́ lónìí tíì ṣe ọjọ́ Ẹtì, ọjọ́ kọ̀ọ̀kandinlọ́gún oṣù kẹfà Ọdun 2026.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkìtì ti kéde ìsinmi lenu isẹ fún àwọn òṣìṣẹ́ lónìí tíì ṣe ọjọ́ Ẹtì, ọjọ́ kọ̀ọ̀kandinlọ́gún oṣù kẹfà…

Ka siwaju

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti kéde ọjọ́ ajé tíì ṣe ọjọ́ kọ̀ọ̀kandinlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà Ọdun 2026 yii ni ìdánwò junior WAEC yóò wáyé ní ìpínlẹ̀ náà.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti kéde ọjọ́ ajé tíì ṣe ọjọ́ kọ̀ọ̀kandinlọ́gbọ̀n oṣù kẹfà Ọdun 2026 yii ni ìdánwò junior WAEC…

Ka siwaju