Ọlọ́pàá Nàìjíríà ti jẹ́rìí sí ìtúsílẹ̀ àwọn olùjọ́sìn CAC Eda Oniyo ní Ìpínlẹ̀ Ekiti lẹ́yìn tí wọ́n ti lo oṣù mélòó kan pẹ̀lú nínú ìgbèkùn àwọn agbésùnmọ̀mí.

Ọlọ́pàá Nàìjíríà ti jẹ́rìí sí ìtúsílẹ̀ àwọn olùjọ́sìn CAC Eda Oniyo ní Ìpínlẹ̀ Ekiti lẹ́yìn tí wọ́n ti lo oṣù…

Ka siwaju

Ilé ẹjọ́ pàṣẹ fún àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà láti gbé ẹjọ́ sájẹ́ǹtì ọlọ́pàá tí ó pa Kabiru awakọ, kí wọ́n sì san owó ìtanràn igba mílíọ̀nù náírà N200M fún pípa awakọ̀ ọkọ̀ akẹ́rù Kabiru Babai ní ọdún 2021 ní ìpínlẹ̀ Osun.

Ilé ẹjọ́ pàṣẹ fún àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà láti gbé ẹjọ́ sájẹ́ǹtì, kí wọ́n sì san owó mílíọ̀nù igba N200M fún…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Ondo dojú ìjà kọ àwọn agbésùmọ́mí ajínigbé,wọ́n da ìbọn bolẹ̀ wọ́n sì gba ìyà àgbà obìnrin ọmọ ọdún mọ́kànlélọ́gọ́ta là nílu Ọwọ.

Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Ondo kojú ìjà, da ìbọn bolẹ̀ fún àwọn agbésùmọ́mí ajínigbé, wọ́n sì gba ìyà àgbà obìnrin…

Ka siwaju

Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó ní àléébù àkàndá ènìyàn tí ó tó ẹgbẹ̀rún mẹ́rìn ó lè igba lé méjìdínlógún ló ti gba ìwé àṣẹ láti wọ ilé ẹ̀kọ́ gíga, ìmọ̀ – ẹ̀rọ àti kọ́lẹ́ẹ́jì ni gbogbo orilẹ-èdè Nàìjíríà láàrin ọdún mẹ́wàá.

Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó ní àléébù tó tó ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ó lé méjìdínlógún ó lé mẹ́rìndínlógún (4,216) ló ti gba ìwé…

Ka siwaju

Àwọn olùkọ́ ní Ọ̀yọ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ wọn bí àníyàn ṣe ń pọ̀ sí lórí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ ti wọn ji gbé, Àwọn ilé ìwé ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tún ti ṣí sílẹ̀ lónìí, bí Ẹgbẹ́ Àwọn Olùkọ́ ní Nàìjíríà ((NUT) ti kéde

Àwọn ilé ìwé gbogbogbò ní Ìpínlẹ̀ Oyo tún ṣí sílẹ̀ lónìí, bí Ẹgbẹ́ Àwọn Olùkọ́ ní Nàìjíríà ti kéde ní…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá ilẹ̀ Gúúsù Áfíríkà(South Africa) ṣe àtìlẹ́yìn fún àwọn olùfẹ́hónúhàn olùfẹ̀sùn láìsí pípa wọ́n,’ akọ̀ròyìn CNN sọ fún Nàìjíríà, Kẹ́ńyà, àti àwọn ilẹ̀ Afrika mìíràn láti kọ́ ẹ̀kọ́ lórí ohun tó ṣẹlẹ̀ ni South Africa .

Àwọn ọlọ́pàá ilẹ̀ Gúúsù Áfíríkà(South Africa) ṣe àtìlẹ́yìn fún àwọn olùfẹ́hónúhàn olùfẹ̀sùn láìsí pípa wọ́n,’ akọ̀ròyìn CNN sọ fún Nàìjíríà,…

Ka siwaju