Tinubu Múra Láti Ṣe Irin-àjò àṣírí lọ sí Mecca Láìròtẹ́lẹ̀ Ṣáájú Àwọn Ètò-ìdìbò Ọdún 2027; Yóò sì Bá Àwọn Gómìnà Márùn-ún, Àwọn Mínísítà Méjì, Olórí Àwọn Òṣìṣẹ́ Rẹ̀, àti Àwọn Míràn Lọ.

ÌRÒYÌN PÀTÀKÌ: Tinubu Múra Láti Ṣe Irin-àjò Àṣírí sí Mecca Kí Àkókò Ìdìbò ti Ọdún 2027 Tó Dé; Yóò sì…

Ka siwaju

Agbésùnmọ́mí tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Dago Sale sọ pe ọmọ-ogun Nàìjíríà kan má ń pèsè ìbọn fún ẹgbẹ àwọn, o si tún sọ pe wọn gba owo ìtúsílẹ̀ tó tó bílíọ̀nù kan náírà .

Bandit kan sọ pe ọmọ-ogun Naijiria kan n pese ibọn fun ẹgbẹ awọn ọdaràn Agbéṣùnmọ̀mí , o si tun sọ…

Ka siwaju

Àárẹ̀ Tinubu wá ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Ilé Aṣojú fún àwọn àwin owó yíyá láti òkè-òkun tó tó $20.52 bilionu àti €1.045 billion.

Tinubu wá ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Ilé Aṣojú fún àwọn àwin owó yíyá láti òkè-òkun tó tó $20.52 bilionu àti €1.045 bílíọ̀nù. Tinubu…

Ka siwaju

Bí Ẹ̀ka NSCDC ní Ìpínlẹ̀ Niger Ṣe Parọ́ nípa Ìbẹ́sílẹ̀ Àrùn Lẹ́yìn tí Àwọn Ènìyàn 33 tó wà kusa lọ́nà àìtọ́ tí Wọ́n Gbé Sínú Àhámọ́ Kú.

Bí Ẹ̀ka NSCDC ní Ìpínlẹ̀ Niger Ṣe Parọ́ nípa Ìbẹ́sílẹ̀ Àrùn Lẹ́yìn tí Àwọn Ènìyàn 33 to wa KÙṢÀ lónà…

Ka siwaju

Ọjọ́ kọ̀ọ̀kanlélogun 21 Lẹ́yìn Tí Ọkọ̀-òfurufú NAF Já, Àwọn Ìdílé Sọ Pé Àwọn Kò Rí Òkú Kankan Nínú Pẹ̀tẹ̀lẹ̀ Oní-erẹ̀ ní Ondo.

Ọjọ́ kọ̀ọ̀kanlélogun 21 Lẹ́yìn Tí Ọkọ̀-òfurufú NAF Já, Àwọn Ìdílé Sọ Pé Àwọn Kò Rí Òkú Kankan Nínú Pẹ̀tẹ̀lẹ̀ Oní-erẹ̀…

Ka siwaju

Àwọn olùwádìí fi ẹ̀sùn kan Siyaka, olórí àjọ NSCDC ní ìpínlẹ̀ Niger, fún fífi ènìyàn kún ibi tí ó pọ̀ jù àti fífúnni ní ìròyìn èké nípa àìsàn kan, lẹ́yìn tí àwọn òṣìṣẹ́-méènù (miners) 33 kú nígbà tí wọ́n wà lábẹ́ àmójútó wọn.

Àwọn olùwádìí fi ẹ̀sùn kan Siyaka, olórí àjọ NSCDC ní ìpínlẹ̀ Niger, fún fífi ènìyàn kún ibi tí ó pọ̀…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Zamfara ti mú ọmọ ẹgbẹ́ JIBWIS kan tó jẹ́ ọmọ ọdún méjìlélógún 22, nítorí fídíò kan tó ti tàn káàkiri, nínú èyí tí ó ti pe fún lílo ìbọn AK-47 láti pa àwọn Kristẹni ní Enugu àti Jos.

Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Zamfara ti mú ọmọ ẹgbẹ́ JIBWIS kan tó jẹ́ ọmọ ọdún méjìlélógún 22, nítorí fídíò kan…

Ka siwaju