Àwọn ọkùnrin mẹ́jọ tí ọjọ́ orí wọn wà láàárín ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún sì méjìlélọ́gbọ̀n ni wọ́n fi ẹ̀sùn kàn lórí ètò láti kọlu ayẹyẹ UFC ti Trump ní Ilé Ààrẹ ni White House.

Àwọn ọkùnrin mẹ́jọ tí wọ́n fi ẹ̀sùn kan pé wọ́n fẹ́ kọlu ìjà ogun onípele-ìdárayá kan ní Ilé Ààrẹ Donald…

Ka siwaju

Àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà mú obìnrin ọmọ orilẹ-èdè Chad tí wọ́n fẹ̀sùn kàn pé ó ń fún àwọn agbésùmọ́mí Boko Haram àti ISWAP ní, oúnjẹ, oògùn olóró àti ọtí líle ní Borno.

Ọwọ́ àwọn ológun orilẹ-èdè Nàìjíríà ti tẹ arábìnrin kàn Racheal Samuel ẹni ọdun mejidinlaadota(48), ọmọ orílẹ̀ èdè Chad 🇹🇩 ,Owo…

Ka siwaju

Gbogbo ọmọ ogun Nàìjíríà tó bá dúró de àṣẹ kí ó tó yinbọn pa àwọn apànìyàn agbésùmọ́mí ni wọ́n máa ń ṣe bí ọlọ́ṣà – Minisita fún ààbò Musa Christopher

Gbogbo ọmọ ogun Naijiria tó bá dúró de àṣẹ kí ó tó yinbọn sí àwọn apànìyàn agbésùmọ́mí ni wọ́n máa…

Ka siwaju

Lórí ọ̀rọ̀ Ìjínigbé: MACBAN bẹ Gómìnà Ọ̀yọ́ , Makinde, fi ẹ̀sùn kan Sunday Igboho fún fífi ìwé àṣẹ sílẹ̀ láti halẹ̀ mọ́ àwùjọ Fulani.

Lórí ọ̀rọ̀ Ìjínigbéc: MACBAN bẹ Gómìnà Oyo, Makinde, fi ẹ̀sùn kan Sunday Igboho fún fífi ìwé àṣẹ sílẹ̀ láti halẹ̀…

Ka siwaju

Ìjà ńlá bẹ́ sílẹ̀ láàárín Hausa àti Yorùbá ni ọjọọ Ìbàdàn, Hausa fi ọ̀bẹ gún ọmọdékùnrin Yorùbá tó lọ ra indomie jẹ́ pa, tí wọ́n sì ń yinbon sókè lákọlàkọ.

Ìjà ńlá bẹ́ sílẹ̀ láàárín Hausa àti Yorùbá ni ọjọọ Ìbàdàn, Hausa fi ọ̀bẹ gún ọmọdékùnrin Yorùbá tó lọ ra…

Ka siwaju

Iléeṣẹ́ ìmọ́tótó àyíká ìjọba ìpínlẹ̀ Eko tí mú àwọn ‘alagbe’ oníbáárà 396, o si ti bẹrẹ ìlànà lati da wọn pada si awọn ipinlẹ abinibi wọn.

Iléeṣẹ́ ìmọ́tótó àyíká ìjọba ìpínlẹ̀ Eko tí mú àwọn ‘alagbe’ oníbáárà 396, o si ti bẹrẹ ìlànà lati da wọn…

Ka siwaju