Àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ́mí gba 50 mílíọ̀nù náírà, àwọn ohun-mímu ẹlẹ́rìndòdò Malt àti oúnjẹ àti èso, kí wọ́n tó tú Adájọ́ Ilé-ẹjọ́ Gíga ti ìpínlẹ̀ Kebbi tí wọ́n jí gbé sílẹ̀ – Ìbátan rẹ̀ ṣàlàyé.

Àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ́mí gba 50 mílíọ̀nù náírà, àwọn ohun-mímu ẹlẹ́rìndòdò Malt àti oúnjẹ èso kí wọ́n tó tú Adájọ́ Ilé-ẹjọ́…

Ka siwaju

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ekiti, Oyebanji, ló ní ọwọ́ nínú bí wọ́n ṣe jí ìyá mi gbé — Ọmọbìnrin Olawumi, ẹni tí ó ti fìgbà kan díje dupò Gómìnà lábẹ́ ẹgbẹ́ APC, ké gbàjarè síta, ó sì ń bẹ̀bẹ̀ fún ìtúsílẹ̀ rẹ̀.

Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn náà rèé lẹ́kùn rẹ́rẹ́: Ọjọ́ kẹta oṣù Kẹjọ, ọdún 2026ÌròyìnOlolade ṣàlàyé pé àwọn ọkùnrin tí a kò mọ̀,…

Ka siwaju

‘Ẹ jọ̀wọ́, ẹ ṣàánú wa’: Àwọn ẹbí,, ìyá bàbá rawọ ẹ̀bẹ̀ fún Gómìnà àti Emir Ilorin ìpínlẹ̀ Kwara láti gba àwọn ọmọ tí àwọn agbésùnmọ́mí jí gbé là.Ẹ jọ̀wọ́, ẹ ṣàánú wa’: Àwọn ẹbí,, ìyá bàbá rawọ ẹ̀bẹ̀ fún Gómìnà àti Emir Ilorin ìpínlẹ̀ Kwara láti gba àwọn ọmọ tí àwọn agbésùnmọ́mí jí gbé là.

‘Ẹ Jọ̀wọ́, Ẹ Ṣe Àánú Fún Wa’: Àwọn Ìdílé Bẹ̀bẹ̀ fún Gómìnà Kwara àti Emir Láti Gba Àwọn Ọmọ tí…

Ka siwaju

Ó pọn dandan fún APC láti borí nínú ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun,’ Alága Àpapọ̀ sọ bẹ́ẹ̀; ó ní wọn yóò kó àwọn Gómìnà, àwọn Àgbà-òjíṣẹ́, àti àwọn mìíràn wá láti kópa nínú ìdìbò náà.’A gbọ́dọ̀ borí nínú ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun fún ẹgbẹ́ APC,’ ni Alága Orílẹ̀-èdè sọ; yóò sì kó àwọn Gómìnà, àwọn Mínísítà, àti àwọn mìíràn wá láti kópa nínú ìdìbò náà.

Ó pọn dandan fún APC láti borí nínú ìdìbò ìpínlẹ̀ Osun,’ Alága Àpapọ̀ sọ bẹ́ẹ̀; ó ní wọn yóò kó…

Ka siwaju