Àbùkù fún Orílẹ̀-èdè bí Àwọn Ẹgbẹ́ Ọlọ́pàá Méjì ní Nàìjíríà ṣe Kọlu Ara Wọn ní Àdúgbò kan ní Ìpínlẹ̀ Ọṣun; Àwọn Olùgbé Wà nínú Ìpayà nítorí Ìró Ìbọn.

ÌRÒYÌN PÀTÀKÌ: Àbùkù fún Orílẹ̀-èdè bí Àwọn Ẹgbẹ́ Ọlọ́pàá Méjì ní Nàìjíríà ṣe Kọlu Ara Wọn ní Àdúgbò kan ní…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun mú obìnrin kan lẹ́yìn tí ọmọ-ẹgbẹ́ ààbò àdúgbò kan kú nígbà tí wọ́n ń ṣe ìbálòpọ̀ ní ìlú Ilé-Ifẹ̀.

Àwọn ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun mú obìnrin kan lẹ́yìn tí ọmọ-ẹgbẹ́ ààbò àdúgbò kan kú nígbà tí wọ́n ń ṣe…

Ka siwaju

Ọlọ́pàá Canada mú ọkùnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33) fún ẹ̀sùn ìfipábá-ni-lòpọ̀ sí obìnrin méjì, tí kò tíì pé ọmọ ọdún méjìdínlógún, ní orílẹ̀-èdè Kánádà(Canada).

Ọlọ́pàá Canada mú ọkùnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33) fún ẹ̀sùn ìfipábá-ni-lòpọ̀ sí obìnrin méjì,…

Ka siwaju

Ìjọ Redeem RCCG ṣètọrẹ, wọ́n san $265,854 láti gbé awọn ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà 500 kúrò ni South Africa lákòókò àwọn ìkọlù tí ó dá lórí ìkórira sí àwọn àjèjì.

Ìjọ Redeem RCCG ṣètọrẹ, wọ́n san $265,854 láti gbé awọn ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà 500 kúrò ni South Africa lákòókò àwọn…

Ka siwaju

Àwọn òṣìṣẹ́ Yunifásítì Ondo ṣe ìwọ́de láti fi ẹ̀hónú hàn nípa bí ìjọba Aiyedatiwa ṣe kùnà láti ṣe àgbékalẹ̀ àdéhùn owó-oṣù tuntun.

Àwọn òṣìṣẹ́ Yunifásítì Ondo ṣe ìwọ́de láti fi ẹ̀hónú hàn nípa bí ìjọba Aiyedatiwa ṣe kùnà láti ṣe àgbékalẹ̀ àdéhùn…

Ka siwaju

Lábẹ́ ìṣàkóso Tinubu, APC lè pàdánù ìbò àwọn ipinlẹ kan ni Gúsù -ÌwọÒòrùn , ko si si ohun ti yóò ṣẹlẹ̀, ilé ayé kò nítorí rẹ̀ wó tàbí parẹ́ — Gómìnà Èkó , Sanwo-Olu

Lábẹ́ Tinubu, APC lè pàdánù ìbò àwọn ipinlẹ kan ni Gúsù -ÌwọÒòrùn , ko si si ohun ti yóò ṣẹlẹ̀,…

Ka siwaju

àwọn ọmọ-ogun Nàìjíríà kọlu ibi tí àwọn oníjàgídígan agbesunmomi ń fi ara pamọ́ sí, wọ́n sì mú àwọn ènìyàn márùn-ún ní ìpínlẹ̀ Taraba.

Àwọn ọmọ-ogun ẹgbẹ́ Joint Task Force (JTF) lábẹ́ ìṣe-ogun Operation WHIRL STROKE ti mú kí àwọn iṣẹ́ wọn tí ó…

Ka siwaju