Àwọn olùjọsìn ECWA márùn-ún tí wọn jí gbé nílùú Omugo Kwara, pẹ̀lú Ìyàwó Pásítọ̀ ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn agbésùnmọ̀mí.

Àwọn olùjọsìn ECWA márùn-ún tí wọn jí gbé nílùú Omugo Kwara, pẹ̀lú Ìyàwó Pásítọ̀ ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn…

Ka siwaju

Àwọn asofin ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Kọ̀ jálẹ̀ láti dúnàdúrà pẹ̀lú àwọn agbéṣùmọ̀mí tó jí àwọn ọmọ ilé ìwé àti àwọn olùkọ́ gbé lọ ní ìjọba ìbílẹ̀ Oriire ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.

Àwọn asofin ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Kọ̀ jálẹ̀ láti dúnàdúrà pẹ̀lú àwọn agbéṣùmọ̀mí tó jí àwọn ọmọ ilé ìwé àti àwọn olùkọ́…

Ka siwaju

Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ ti ìjọba àpapọ̀ ti dájọ́ ikú fún àwọn agbésùnmọ̀mí Al-Shabaab mẹ́rin to ṣe ìkọlù ìpakúpa tí wọ́n pa àwọn olùjọsìn ní Ṣọ́ọ̀ṣì St. Francis Kátólíìkì tìlú Ọ̀wọ̀.

Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ ti ìjọba àpapọ̀ ti dájọ́, ìdájọ́ ikú fún àwọn agbésùnmọ̀mí Al-Shabaab mẹ́rin lórí ìpakúpa tí…

Ka siwaju

Awọn agbebọn ji iyawo,àti awọn ọmọ ibeji arákùnrin àbúrò minisita fún ètò iná mọ̀nàmọ́ná tẹlẹri Adebayo Adelabu gbé lọ nilu Ìbàdàn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.

Awọn agbebọn ji iyawo,àti awọn ọmọ ibeji arákùnrin àbúrò minisita fún ètò iná mọ̀nàmọ́ná tẹlẹri Adebayo Adelabu gbé lọ nilu…

Ka siwaju

Seyi Makinde bu ẹnu atẹ lu awọn ọrọ ti Fayose sọ , lórí àwọn ọmọ ilé ìwé àti àwọn olùkọtí àwọn agbésùmọ́mí jí gbé ní Ọ̀yọ́, o rọ ara ilu kí wọn gbàdúrà fun un.

Makinde bu ẹnu atẹ lu awọn ọrọ ti Fayose sọ , lórí àwọn ọmọ ilé ìwé àti àwọn olùkọ́ tí…

Ka siwaju

Awọn òṣìṣẹ́ Olukọni yawọ ọ́fíìsí ijoba, ọ́fíìsí Gómìnà Enugu, láti fẹ̀hónúhàn lórí Awọn ọmọ ile-iwe àti olùkọ́ ti wọn ji gbé lọ ní Ọ̀yọ́ .

Awọn Olukọni yawọ ọ́fíìsí Gómìnà Enugu ijọba Enugu, láti fẹ̀hónúhàn lórí Awọn ọmọ ile-iwe àti olùkọ́ Oyo ti wọn jigbe.…

Ka siwaju

Bokoharam kéde pé àwọn fẹ́ ṣe ayẹyẹ ìparí ẹ̀kọ́ Al-Quran fún ọgọ́rùn-ún (100) nínú àwọn obìnrin àti àwọn ọmọ tí wọ́n jí gbé ní ìjọba Kaiama Kwara I to tí kẹ́kọ̀ọ́ yege ni àhámọ́ wọn.

Bokoharam kéde pé àwọn fẹ́ ṣe ayẹyẹ ìparí ẹ̀kọ́ Al-Quran fún ọgọ́rùn-ún (100) nínú àwọn obìnrin àti àwọn ọmọ tí…

Ka siwaju