Ìyàlẹ́nu bo gbogbo ènìyàn bí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Yunifásítì Jos ṣe dáyà jẹ ẹlẹgbẹ́ wọn títí ó fi kú nítorí ẹ̀rọ ibanisoro iPhone kan tí ó sọnù; àwọn ọlọ́pàá sì dákẹ́ jẹ́ẹ́.

Ìyàlẹ́nu bo gbogbo ènìyàn bí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Yunifásítì Jos ṣe dáyà jẹ ẹlẹgbẹ́ wọn títí ó fi kú nítorí ẹ̀rọ…

Ka siwaju

Ọ̀gá ọlọ́pàá Tunji Disu ti pàṣẹ fún àwọn ọlọ́pàá láti yinbọn lu ẹnikẹ́ni tí kìí se eléso ààbò tàbí ológun tí wọn ba ri tí ó gbé ohun-ija ìbọn ti ko bofin mú dání..

Ọ̀gá ọlọ́pàá Tunji Disu, sọ pé wọ́n tí fún àwọn ọlọ́pàá ní àṣẹ láti ta ẹnikẹ́ni tí wọ́n bá rí…

Ka siwaju

Àárẹ̀ ilẹ̀ Amẹ́ríkà, Donald Trump, gboriyin fun ọba Morocco Mohammed VI, fún aṣeyọrí iṣẹ́ òpópónà ńlá kìlómítà (1,055)Tiznit-Dakhla, O kede ni ọjọ́ aiku pé wọ́n yóò sọ ọ̀nà gíga Tiznit-Dakhla tí orilẹ-èdè Morocco ní orúkọ òun.

Trump kede pe wọn yoo fun ọna nla Tiznit–Dakhla ni orukọ rẹ, o si dupẹ lọwọ Ọba Mohammed VI. Ààrẹ…

Ka siwaju

Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà Nàìjíríà tí fọwọ́sí ìwé òfin lati fi òfin de ìwàásù nínú àwọn ọkọ̀ èrò ìrìn àjò gbogboogbò, ẹni tí ó bá tapa sòfin yóò san Àádọ́ta ẹgbẹ̀rún náírà.

Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà Nàìjíríà tí fọwọ́sí ìwé òfin lati fi òfin de ìwàásù nínú àwọn ọkọ̀ èrò ìrìn àjò…

Ka siwaju

Sheikh Gumi bèrè ìdí tí kò fi sí òṣìṣẹ́ Ìjọba Tinubu kankan tí ó ti lọ pàdé awọn ọmọ ẹgbẹ ikọ̀ Boko Haram tàbí lọ bá àwọn ọlọ́ṣà agbésùmọ́mí fún ijiroro ìpàdé àlàáfíà , gẹ́gẹ́ bí Jonathan àti Osinbajo ti ṣe pẹ̀lú àwọn ọlọ̀tẹ̀ oníjàgídíjàgan agbègbè Niger Delta (Niger Delta militants) .

Sheikh Gumi bèrè ìdí tí kò fi sí òṣìṣẹ́ Ìjọba Tinubu kankan tí ó ti lọ pàdé awọn ọmọ ẹgbẹ…

Ka siwaju

Ọmọ ẹni ti o da ile-iṣẹ ọ̀kín bisikiiti silẹ sọrọ nipa iroyin ipadabọ awọn bisikiiti OkinIle-iṣẹ Okin Industries sọ pe awọn ṣe ìgbìyànjú lati tun mu ami-ọja bisikiiti Okin ti o gbajumọ pada wa si ipo rẹ ṣi n lọ lọwọ, eyi ti o n funni ni ireti pe yoo pada wa si orilẹ-ede Naijiria gẹgẹ bi ọpọlọpọ ti n reti rẹ láìpẹ́ .

Ọmọ ẹni ti o da ile-iṣẹ naa silẹ sọrọ nipa iroyin ipadabọ awọn bisikiiti OkinIle-iṣẹ Okin Industries sọ pe awọn…

Ka siwaju

Awọn onijagidijagan Agbésùmọ́mí pa awọn ọlọpaa mẹrin ati awọn oṣiṣẹ aabo, wọn si ji Alaga Ijọba Ibilẹ Zamfara ati iyawo rẹ gbé lọ ni Bungudu.

Awọn onijagidijagan Agbésùmọ́mí pa awọn ọlọpaa mẹrin ati awọn oṣiṣẹ aabo, wọn si ji Alaga Ijọba Ibilẹ Zamfara ati iyawo…

Ka siwaju

Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá mú àwọn òṣìṣẹ́ ọlọ́pàá mẹ́rin lẹ́yìn tí fídíò wọn jáde sórí ayélujára tó fi ẹ̀tanú ẹlẹ́yàmẹyà hàn, fa ìbínú gbígbóná janjan, tí wọ́n sì ń bèrè owo lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà tó ń bọ̀ láti UK.

Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá mú àwọn òṣìṣẹ́ ọlọ́pàá mẹ́rin lẹ́yìn tí fídíò wọn jáde sórí ayélujára tó fi ẹ̀tanú ẹlẹ́yàmẹyà hàn, fa…

Ka siwaju

Adeleke fagile awọn iṣẹ-ṣiṣe ẹgbẹ NURTW ni ipinlẹ Osun, o si paṣẹ pe ki a mu awọn ti o ba tako aṣẹ yii.Adeleke tun fun awọn ọlọpaa ati awọn ile-iṣẹ aabo miiran ni aṣẹ lati mu awọn ti o ba tako aṣẹ yii fun igbesẹ ofin ti o le tẹle e.

Adeleke fagile awọn iṣẹ-ṣiṣe ẹgbẹ NURTW ni ipinlẹ Osun, o si paṣẹ pe ki a mu awọn ti o ba…

Ka siwaju