Ọga agba iléèwé Ọyọ ti wọn jigbe pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sọ pé kii sẹ owo biliọnu kan naira,ọkọ̀ Hilux méjì àti òfin Sharia ni àwọn agbesunmobi ń bèrè fún ò.

Ọga agba ileewe Ọyọ ti wọn jigbe pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sọ pé kii sẹ owo biliọnu kan naira,ọkọ̀ Hilux méjì…

Ka siwaju

Orílẹ̀ èdè Iran ṣe ìfọlọ́lè àwọn misaili tuntun fún Israeli fún ìgbà àkọ́kọ́ láti inú oṣù kẹrin àdéhùn jogunomi ni àárín Ìlà-Oòrùn.

Iran ṣe ifilọlẹ awọn misaili tuntun fún Israeli fun igba akọkọ lati inú oṣù kẹrin àdéhùn jogunomi ni àárín Ìlà-OòrùnỌjọ́…

Ka siwaju

Àwọn Ọlọ́pàá ri aṣọ ọlọ́pàá méjì gba lọwọ awọn afurasi awọn Fulani ajinigbe ni ìpínlẹ̀ Ogun, ti wọn si ti pa awọn èèyàn méjì ni Ẹdo .

Oṣu Kẹfa Ọjọ Kẹfà , Ọdun 2026IroyinOrúkọ Àwọn afurasí méjì náà ni Gafaru Adamu, ẹni ọdun marundinlogbon 25 ati Muhammed…

Ka siwaju

Boko Haram gé orí àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà, àwọn kan farapa yánnayànna bí wọ́n ṣe ṣe Ìkọlù sí ọgbà ológun ni kùtùkùtù òwúrọ̀ òní ọjọ́ Ẹtì ni ibùdó àwọn ọmọ ogun tó wà ni ìpínlè Borno.

Loni tíì ọjọ́ Ẹtì ọjọ́ Kàrún oṣù kẹfà ọdún 2026 ni àwọn Boko Haram gé orí àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà,…

Ka siwaju

Arábìnrin tó ń ta Ẹ̀wà ń pa N20,000 lóojojúmọ́ n’ilu Esiele :Ó rò pé òwò òun gbòòrò sí i ni, láì mọ̀ wípé àwọn agbésùnmọ̀mí ni òun tajà fún – Sínetọ̀ Ọ̀yọ́

Arábìnrin tó ń ta Ẹ̀wà yìí ń pa N20,000 lóojojúmọ́ n’ilu Esiele :Ó rò pé òwò òun gbòòrò sí i…

Ka siwaju

Awọn Agbéṣùmọ̀mí ji Olukọni Shina Adeoye tí Ile-iwe alakọbẹrẹ Cooperative Primary school Eruku Kwara gbé ni ọna rẹ bí ó ṣe ń lọ síbi iṣẹ.

Awọn Agbéṣùmọ̀mí ji Olukọni Shina Adeoye tí Ile-iwe alakọbẹrẹ Cooperative Primary school Eruku Kwara gbé ni ọna rẹ bí ó…

Ka siwaju