
Ìròyìn Tó ń lọ











Igbákejì Ààrẹ Nàìjíríà Kashim Shettima dé sí Ondo fún ti ayẹyẹ ọgọ́rùn-ún ọdún ọjọ́ ìbí Reuben Fasoranti. Igbákejì orílẹ̀ èdè…
Ka siwaju
Ìlú Èkó ṣe òfin ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn to ń lo iná mọnamọna n’ilu Èkó. Ilu Eko ṣe ofin iranlọwọ…
Ka siwaju
Àwọn Agbéṣùmọ̀mí jihadist Ai qeuda ṣe ìkọlù tuntun sí Mali ni agbègbè aringbungbun Mali wọn pa ọpọlọpọ eniyan, awọn Ọlọ́dẹ…
Ka siwaju
Minisita ti wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ yan fun Agbára iná mànàmáná , Joseph Olasunkanmi Tegbe, ti kọ awọn iroyin ti o sọ…
Ka siwaju
Arábìnrin Aláboyún tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Love Marcus bímọ sí ibùbá àwọn agbésùnmọ̀mí, lẹ́yìn ó san N77milionu. Arábìnrin Aláboyún…
Ka siwaju
ÀṢÀKẸ́ TV SHOW: Sínetọ̀ ile-igbimọ ti o nsoju Edo North, Sínetọ̀ i Adams Oshiomhole, ni Ọjọbọ̀ ọjọ́ keje oṣù karùn-ún…
Ka siwaju
Ààrẹ Tinubu ti yan Ìyà àárín Arinola Ogbara Banjoko gẹ́gẹ́ bí Alákóso aṣojú lórí ìgbìmò ìṣòwò pàsí pààrọ̀ ọjà ìpínlẹ̀…
Ka siwaju
Ọ̀gá ọlọ́pàá Tunji Disu, n wá , ajọṣepọ ìfọwọ́sowopo àwọn ọlọ́pàá àti àwọn ará ìlú agbègbè láti ni ètò ààbò…
Ka siwaju
Nnamdi Kanu, Agbẹjọro AMẸRIKA láti ṣe ìkéde ‘ìKéde Sokoto’ Lori Biafra Ipinnu Ara-ẹni ni ọ̀gbọ́n ọjọ́ Oṣu Kàrún 2026 .…
Ka siwaju
ÀṢÀKẸ́ TV NEWS : Idoko-owo ọmọ-ogun ni awọn drones lati jẹki awọn iṣẹ ṣiṣe – COASỌ̀gá iléeṣẹ́ ológun Lieutenant General…
Ka siwaju