Gómìnà Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ Seyi Makinde ni àárọ̀ òní tíì ṣe ọjọ́ Àbámẹ́ta, Ọgbọ̀n ọjọ́ Oṣù Kàrún 2026, kó Ọgọọgọrun àwọn ọkọ̀ ayọkẹlẹ tí ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn irinṣẹ ìbániẹnisọ̀rọ̀ fún àwọn ilé isẹ ààbò ni ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ pẹ̀lú àwọn ọlọ́pàá.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ Seyi Makinde ni àárọ̀ òní tíì ṣe ọjọ́ Àbámẹ́ta, Ọgbọ̀n ọjọ́ Oṣù Kàrún 2026, kó Ọgọọgọrun àwọn…

Ka siwaju

Ọwọ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ogun tẹ Abdullahi Muhammadu Seriki Fulani Ijebu Ode àti ọmọ rẹ̀ ọkùnrin, wọn ri àpò owó tí wọ́n fi gba owó ìtúsílẹ̀ “Ransom “níbi ilé ìdáná rẹ̀.

Ọwọ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ogun tẹ Abdullahi Muhammadu Seriki Fulani Ijebu Ode àti ọmọ rẹ̀ ọkùnrin, wọn ri àpò owó tí…

Ka siwaju

Lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ méjì Mínísítà fún ètò ẹ̀kọ́ bẹnu àtẹ́ ìkọlù bí àwọn agbésùnmọ̀mí ṣe jí àwọn ọmọ ilé ìwé àti àwọn olùkọ́ gbé ní Ọ̀yọ́ àti Borno.

Lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ méjì Mínísítà fún ètò ẹ̀kọ́ bẹnu àtẹ́ ìkọlù bí àwọn agbésùnmọ̀mí ṣe jí àwọn ọmọ ilé ìwé àti…

Ka siwaju

Ẹ na ẹnikẹ́ni tí ó bá tako òfin Sharia, Mufti tí Ìlú Iwo, Sheikh Daood Imran Molaasan ti rọ àwọn Mùsùlùmí láti na ẹnikẹ́ni ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tí ó bá tako ìdásílẹ̀ òfin Sharia.

Mufti ti ìlú Iwo, Sheikh Daood Imran Molaasan, ti ro àwọn Mùsùlùmí lati lu ẹnikẹ́ni ni ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti o…

Ka siwaju